Gómìnà Adekele gbaṣẹ́ lọ́wọ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí Oyetola gbà síṣẹ́ lẹ́yìn ìbò

Aworan

Oríṣun àwòrán, Others

Ijoba ipinle osun ti kede pe awoͅn ti yoͅ awoͅn osͅisͅeͅ ti woͅn gba si eͅnu isͅeͅ loͅna eͅburu kuro ni ipinleͅ Osun.

Woͅn awoͅn ti woͅn gba si eͅnu isͅeͅ loͅna eͅburu yii wa lati oͅdoͅ ijoͅba to kuro ni ori oye.

Bakan naa ni woͅn fikun un pe ko si bi ijoͅba ana sͅe le dunkoko moͅ woͅn to, awoͅn ko n iyi ipinnu woͅn pada.

Ninu ateͅjade ti osͅisͅeͅ paaki lori eto ilu, Tunde Busari ni ijoͅba ti fi ero woͅn lede ni ilu Osogbo.

Ijoͅba Oyetola sͅe eru peͅlu awoͅn osͅisͅeͅ ti woͅn gba si isͅeͅ

Tunde Busari ninu ateͅjade naa ni ijoͅba Oyetola labeͅ isͅakoso eͅgbeͅ osͅelu APC ti ko ijoͅba sinu oͅpoͅloͅpoͅ gbese nipa aisͅe otitoͅ nigba ti woͅn wa lori oye

''Awoͅn ti ijoͅba ko si eͅnu isͅeͅ ko ni imoͅ nipa ohun ti woͅn gba woͅn si’’

''Awoͅn naa ni woͅn n feͅhoͅnu han pe woͅn ko gboͅdoͅ yoͅ woͅn nisͅeͅ nitori woͅn gba owo osͅu lai sͅisͅeͅ''

''Nitori naa gbogbo awoͅn ti ijoͅba gba si eͅnu isͅeͅ loͅna eͅburu, ni a ti le danu, ti ko si si eͅni to le gba woͅn pada si eͅnu isͅeͅ.''

Bakan naa ni woͅn kiloͅ fun awoͅn araalu lati masͅe padipoͅ peͅlu ijoͅba ana lati diteͅ moͅ ijoͅba.

Agbeͅnusoͅ fun gomina Ademola Adeleke naa ni ko dara bi ijoͅba ana sͅe gba awoͅn eniyan si isͅeͅ leͅyin to ku dieͅ ko fi ijoͅba sileͅ, ti ko si ni owo lati san owo osͅu fun woͅn.