Mo teͅnumoͅ pe Tinubu kóͅ ni ààreͅ tí wóͅn dìbò yàn– Ayo Adebanjo

Aworan

Oríṣun àwòrán, Others

Adari eͅgbeͅ oͅmoͅ Yoruba, Afenifere, Baba Ayo Adebanjo ti ni o da oun loju pe orileͅede Naijria ko ni aareͅ ti woͅn dibo yan lai fi ti Ajo eleto idibo INEC to kede Bola tinubu geͅgeͅ bi aareͅ to woͅle ni Naijiria.

Baba Adebanjoͅ lo soͅ oͅroͅ yii lasiko to n soͅroͅ lori eͅroͅ Teͅlifisoͅn Arise TV ko si otitoͅ ninu esi idibo to gbe Tinubu woͅle.

O ni laipeͅ ni otitoͅ yoo fi ara han lori esi idibo naa nitori kii se lori ododo ni.

‘’Esi idibo naa safihan ijoͅba ti ko dara, peͅlu igbagboͅ pe opin yoo de ba laipeͅ’’

Igba akoͅkoͅ koͅ niyii ti Baba Adebanjo yoo maa soͅroͅ tako Tinubu

‘’Ohun ti mo le fi da yin loju ni pe ko si aareͅ ti woͅn dibo yan rara, oͅroͅ lori iroͅ lasan ni, ti yoo si fi ara han laipeͅ.’’

‘’Ere orita ni ti gbogbo wa si fi oju ara wa ri, ti a si n wo loͅwoͅloͅwoͅ.’’

‘’Ibeere mi ni pe kilo de ti Ajoͅ INEC ko teͅleͅ ofin to de eto idibo ni Naijiria?’’

Bakan naa ni Pa Adebanjo fikun un pe awoͅn alatileͅyin Tinubu n tako awoͅn ti woͅn ba tabuku oͅga woͅn.

moͅ o ni awoͅn alatileͅyin reͅ ko soͅroͅ lori awoͅn iwadii to jade leͅyin ti ajoͅ INEC kede reͅ.

Igba akoͅkoͅ koͅ niyii ti Baba Adebanjo yoo maa soͅroͅ tako iyansipo Bola Ahmed Tinubu.

Ki idibo si ipo aareͅ naa to waye ni Baba Adebanjoͅ ti fi atileͅyin reͅ han fun oludije leͅgbeͅ oselu Labour Party, Peter Obi geͅgeͅ bi eͅni ti ipo naa toͅsi nitori eͅya Igbo ni.

Ajo INEC ni Tinubu lo woͅle si ipo aareͅ ni Naijiria leͅyin to jawe idibo sipo aareͅ to waye ni Oͅjoͅ Karundinloͅgboͅn, Osu Keji, oͅdun 2023.