#justiceforjennifer: Ta ló fipá bá Jennifer lò pọ̀ ní Kaduna?

Aworan obinrin to leran
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ifipabanilopọ jẹ ẹsun to lagbara pupọ labẹ ofin.

Amọṣa yatọ si pe o lagbara labẹ ofin, kii ṣe iriri to n mu ayọ ba ẹni to ba foju wina rẹ.

Ko sẹni ti wọn ko lee fi ipa ba lopọ, yala akọ tabi abo ṣugbọn lọpọ igba, awọn obinrin lo maa n saba ṣẹlẹ si.

Ni asiko ti iroyin yii jade, iroyin n lọ lori ayelujara nipa ọdọbinrin jojolo kan tawọn ọmọ ọkunrin marun un fi ipa ba lo pọ lọsẹ diẹ sẹyin ni ilu Narayi ni ipinlẹ Kaduna.

Gẹgẹbi ohun ti ọmọ Naijiria kan @Uncle Shemzz fi sita loju opo ayelujara rẹ, ọmọ ọdun mejidinlogun ni ọmọdebinrin naa to pe orukọ rẹ ni Jeniffer.

Ko tii si ẹni lee sọ ohun to pa arabinrin yii atawọn to fipabaalopọ pọ ṣugbọn fidio kan eyi to n lọ kaakiri lori ayelujara ṣafihan ibi ti wọn ti n tọju ọmọdebinrin yii.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Skip X post, 2

End of X post, 2

Iroyin kan tilẹ tun ṣalaye pe ọwọ ti tẹ meji ninu awọn ọmọkunrin to ṣe iṣẹ laabi naa ṣugbọn wọn ko tii fi wọn jofin

Oniruuru ọrọ lawọn ọmọ orilẹede Naijiria si ti n sọ lori ọrọ yii loju opo twitter.

Diẹ lara wọn niyi:

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5

Iroyin ti a ko tii fi idi rẹ mulẹ tilẹ fi kun un pe awọn obi ọmọdebinrin naa tilẹ ti gba lati gba owo gba maa binu lori ọrọ naa ṣugbọn awọn eeyan kan ti bu ẹnu atẹ lu igbesẹ yii eleyi ti wọn ni ko tọna rara

Skip X post, 6
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 6