Daura Ruler: Ọlọ́pàá ti gba àna ẹ̀ṣọ́ ẹ̀yin Buhari silẹ̀ lọ́wọ́ ajínigbé

Musa Umar pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá lẹyin ti ọlọpaa gba silẹ

Oríṣun àwòrán, IRT

Àkọlé àwòrán, Musa Umar pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá lẹyin ti ọlọpaa gba silẹ

Awọn ajinigbe ti da ana ẹsọ ẹyin Aarẹ Muhammadu silẹ lẹyin oṣu meji ati aabọ ti wọn gbe.

Wọn ji Musa Umar, to jẹ Magajin Garin abule Daura ni Ipinlẹ Katsina gbe ni oṣu Kẹrin ọdun 2019.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Ikọ ọlọpaa taa mọ si 'Operation Puff Adder' ati ikọ IRT ti Abba Kyari n dari rẹ, lo parapọ pẹlu awọn ọlọpaa to wa ni Ipinlẹ Kano lati gba baba naa silẹ ni Gangan Ruwa, ni ijọba ibilẹ Kumbotso ni Ipinlẹ Kano lọjọ Aje.

Musa Umar lẹyin ti awọn ọlọpaa gba silẹ

Oríṣun àwòrán, IRT

Àkọlé àwòrán, Musa Umar lẹyin ti awọn ọlọpaa gba silẹ

Awọn alaṣe ni wọn gba Magajin Garin naa silẹ, wọn tun mu awọn afurasi kan pẹlu ibọn.

Musa Umar lẹyin ti awọn ọlọpaa gba silẹ

Oríṣun àwòrán, IRT

Àkọlé àwòrán, Musa Umar lẹyin ti awọn ọlọpaa gba silẹ