Sambisa: Yóò di ibi ìgbàfẹ́ láìpẹ́ ọjọ́

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Olórí àwọn ọmọogun orile-ede Naijiria Tukur Buratai sọ pé ibùdó àwọn Boko Haram tẹ́lẹ̀ rí nínú igbó sambisa kò ní pẹ di ibi ìgbàfẹ́.
Tukur sọ̀rọ̀ yìí lásìkò tí àjọ tó ń rí sì ìrìn-àjò ìgbàfẹ́ sabewo sii.
Ó ní Àjọ tó ń mojuto irinajo ìgbàfẹ́, ìjọba Ìpínlẹ̀ Borno àti àjọ ọmọogun tí ń jíròrò lórí kókó náà.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Ó ní sísọ ìbè di ibi ìgbàfẹ́ yóò fi ìgbàgbé sí àwọn tí tí ṣẹlẹ̀ yóò sì tún mú ìlò igbó Sambisa kojú òṣùwọ̀n








