Ilé-ẹjọ́ ìlú Èkó fi Nwaoboshi sátìmọ́le fún ìkówójẹ

Oríṣun àwòrán, Nwaoboshi /twitter
Ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ tí Ìlú Èkó tí sọ Sẹ́nétọ̀ Peter Nwaoboshi tíì ṣe ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party tó ń soju fún ẹkùn Delta North sewon.
Muhammed Idris dájọ pé kí Nwaoboshi wà látìmọ́lé di ọjọ́ Jimo tí ilé ẹjọ́ yóò fi ṣe àgbéyèwò gbígba oniduro rè.
Àjọ EFCC ló gbé Sẹ́nétọ̀ náà lọ sile ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ikowo ìlú pamọ́.








