Oyo, igi odan kàyééfì: Kò yẹ kí a bọ igi Ọdán yìí nítori pé ẹ̀rọ agégi mẹ́rìn kò rí i ge- Ẹni tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ṣojú rẹ̀

Orisirisi ero ni awọn ti iṣẹlẹ igi Ọdan yii ṣoju wọn ti n sọ sita.
Bi awọn kan ṣe sọ pe ki wọn maa bọ igi yii ni awọn miran ni rara ko yẹ ki wọn maa bọ igi to gba ẹmi awọn eeyan rara.
Lara awọn ti wọn pe ko wa ba wọn ge igi naa lasiko ti wọn n doola ẹmi awọn to wo pa mọlẹ ṣalaye fun BBC pe
- Ẹbọ Oríta: Àwọn òṣìṣẹ́ iná ọba, IBEDC fojú kó ẹbọ ní Magboro torí àìsí iná
- Kéére o! Ojú òpó WhatsApp kò ní ṣiṣẹ́ mọ́ lórí àwọn ẹ̀rọ ìléwọ́ yìí láti Nov 1
- Obìnrin tó bá ń gbé bùkátà kò ní ọkọ kódà kó wà nílé ọkọ - Kemi Afolabi
- Facebook ń ṣàkóbá fún ọpọlọ ọmọdé ó sì ń káàrẹ̀ bá ìjọba àwaarawa, àṣírí tú! - Òṣìṣẹ́ iléeṣẹ́ Facebook
- Ọwọ ọlọ́pàá tẹ afurasí ajínigbé tó máa n dibọn bí dírẹ́bà láti jí àwọn arìnrìnàjò gbé
- Ìyàwó Ganduje ti kúrò lọ́dọ̀ọ́ EFCC, wo ohun tó gbé e lọ síbẹ̀....
- Àwọn Òṣèré fíìmù Yorùbá tẹ́ ò ro tó tí jápaa lọ ìlú Òyìnbó rèé

Alaáfin Oyo ti kan sí ìdí igi to wó, ti ará ìlú gé ní àná tó tun díde padà lónìí-
Alaafin Oyo ti de ibi iṣẹlẹ to ṣẹlẹ ni ilu Oyo.Ọjọ́ burúkú èṣù gbomimú ní Ọyọ! igi ńlá wó pa ọ̀pọ̀ ènìyàn
Igi Odan yii ni wọn ni o wo ti o si ṣe ijamba fun awọn eeyan ti wọn si n yọ wọn sita labẹ igi naa.
Nigba naa ni wọn pe awọn agegi lati wa ba wọn ge igi naa lati doola ẹmi awọin eeyan.
- Ọwọ ọlọ́pàá tẹ afurasí ajínigbé tó máa n dibọn bí dírẹ́bà láti jí àwọn arìnrìnàjò gbé
- Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin yan ẹ̀ní tó tí bẹ̀rẹ̀ iléèwé kí wọ́n tó dé ilé ayé gẹ̀gẹ̀ bí ìgbìmọ̀ Àjọ EFCC
- Ìyàwó Ganduje ti kúrò lọ́dọ̀ọ́ EFCC, wo ohun tó gbé e lọ síbẹ̀....
- Irú àìsàn wo ló ń bá Sunday Igboho finra ní Benin kí sì ní àwọn àgbààgbà Yorùbá n sọ sí ọ́rọ́ yi?
- Ẹ̀yin ọmọ Naijiria, ẹ ṣóra fún ''Frozen Turkey, Chicken'' àwọn ìkà ń fí ''Formalin'' sí i- NAFDAC

Nigba ti ọrọ igi to dide yii n di nkan mii, Alaafin iku Baba Yeye, Adeyemi naa ti kan sibẹ lati ba awọn ara ilu Oyo sọrọ.
Alaafin fi awọn eeyan naa ni ọkan balẹ pe ilu yoo ṣe ohun to yẹ ki iru rẹ ma baa ṣẹlẹ mọ ti yoo maa mu ẹmi awọn eniyan lọ.
Awọn ti iṣẹlẹ naa ṣoju wọn ṣalaye bi wọn ṣe lọ pe ge igi ge igi lati wa ran wọn lọwọ.

Wọn ni pe iyalẹnu lo jẹ fun wọn pe igi naa dide duro pada lonii.
O kere tan eniyan mẹrin lo ba ijamba igi to wo lulẹ lọ lasiko ojo arọrọda ni agbegbe Alafin Sabo Idi Odun ni ipinlẹ Ọyọ.

Iroyin ni ojo arọrọda lo fa ti awọn eniyan to fi mọ ọmọde ati agba ti wọn sa si abẹ igi naa lati duro ki ojo fi da, ki ọlọjọ to de.
Awọn ti iroyin naa ṣoju wọn niawọn ti igi nla naa wọpa yii ni wọn sa fun ojo ti wọn si lọ joko si abẹ igi ọun ti ẹlẹran kan ti ma n ta ẹran labẹ igi nla naa.
- Èkó àti Rivers nìkan kọ, wo àwọn ìpínlẹ̀ Gúúsù-Gúúsù mi tó ṣetán láti lọ sílé ẹjọ́ gíga jùlọ lórí VAT
- À ò ni gbárùkù tì gbogbo ẹ̀yin gómìnà ìhà Gúúsù tó bá tako kíkẹ́ràn jẹ̀ - Miyetti Allah
- Nkechi Blessing sọ̀rọ̀ nípa ikú ìyá rẹ̀, ó tún tú àṣírí kàbìtì nípa ìhùwàsí ara rẹ̀ táyé kò mọ̀
- Kìí ṣe pé ìjọba ń fi ọwọ́ jẹ́jẹ́ mú àwọn jàndùkú o - Lai Mohammed
Ọjọ́ burúkú èṣù gbomimú ní Ọyọ! igi ńlá wó pa ọ̀pọ̀ ènìyàn
Wọn ko pẹ ti ojo naa bẹrẹ ti igi lile tẹlẹ, to si n ṣi awọn orule to fi mọ awọn ile epo to wa ni ayika.
Amọ, awọn to wa ni abẹ igi naa ko tete fun ra pe igi naa fẹ wo ki iṣẹlẹ to mu ẹmi awọn eniyan to wa ni abẹ rẹ lọ.
Awọn ti iroyin naa soju wọn sọ wi pe eniyan mẹsan lo wa ni abẹ igi naa, nigba ti awọn miran ni eniyan mẹrin lo ba iṣẹlẹ
''Lojiji ni iṣẹlẹ yii waye ni irọlẹ ti ojo yii su, eleyii to mu ki awọn eniyan ma a sa lati palẹmọ ki ojo naa to bẹrẹ.''

''Awọn ọkọ n sare ni oju popo ki ojo naa ma ba wọn lọna ki wọn le tete de ibi ti wọn n lọ.''
''Bakan naa ni awọn iyalọja ni agbegbe naa n sare lati tete wọ ọkọ ki ojo naa to bẹrẹ.''
''Amọ ọjọ naa bẹrẹ ni kiakia, ti awọn eniyan si lọ joko ti ẹlẹran labẹ igi lati sa fun ojo yii lai mọ pe ibẹ ni opin yoo de ba wọn.''
''Bio tilẹ ṣepe ojo naa ko rọ lọpọ ju, amọ iji lile tẹle ojo naa, ti o si bẹrẹ si ni ṣi orule ile to fi mọ awọn canopy ti wọn fi bo awọn ileepo to wa ni agbegbe naa.''
''Lẹyin eyi ni igi ti awọn eniyan joko si abẹ rẹ wo lulẹ to si pa awọn iyalọja ati awọn ọmọde to wa ni abẹ igi naa ni agbegbe Oyo Alafin Sabo idi odun.''
Amọ, iroyin miran ti a ko le fi idi rẹ mulẹ ni igi naa to ti le ni ọgọrun ọdun tun dide fun ara rẹ lẹyin to wo pa awọn eniyan tan.
This article contains content provided by Instagram. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read Instagram cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of Instagram post
- Ẹ̀yin ọmọ Yoruba ẹ darapọ̀ mọ́ wa látí tako ìjọba Naijiria lórí àtìmọ́lé Nnamdi Kanu - IPOB
- Àṣírí ọ̀rọ̀ àti dúkìá ìkọ̀kọ̀ ẹbí aarẹ Uhuru Kenyatta tú
- Àwọn dókítà tí fagilé ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ gbọọrọ, sùgbọ́n...
- Ṣé Facebook, Instagram, WhatsApp ti yín náà ti dẹnukọlẹ̀? Ìdí tó fi ṣẹ́lẹ̀ rèé...
- Ẹ yé kóra jọ pọ̀ láti d'ẹ́rù ba ni pé ọwọ́ Yorùbá ni Ààrẹ 2023 gbọ́dọ̀ bọ́ sí- Shekarau
Aworan ati fidio to wa lori ẹrọ ayelujara safihan igi naa to ti ni gbongbo lẹyin to ti hu ti idi ti idi ni irọlẹ ti iṣẹlẹ naa waye.

Oríṣun àwòrán, Others


















