Samuel Oluwafemi sọ bí Covid 19 ṣe bí ìdíje oníjó àti eré fún àwọn Odi àti Adití sí rere

Àkọlé fídíò, Samuel Oluwafemi sọ bí Covid 19 ṣe bí ìdíje oníjó àti eré fún àwọn Odi àti Adití sí rere

Mo fẹ́ràn láti máa kó Odi àti aditi ni, kódà, ọ̀kan nínú wọn ni aya ti mo fẹ́ sílẹ̀- Samuel Oluwafemi

Ogbeni Samuel James Olufemi gbalejo BBC Yoruba nibi to ti n kọ awọn to ni ipenija ara ni ijo jijo ati ere itage ni ṣiṣe.

O salaye bi irinajo yii ṣe bẹre lọdun 2007 nigba to lọ kọ nipa ọna ibanisọrọ nipa lilo ọwọ lẹyin to ka nipa ere itage nile ẹkọ giga.

Deaf

Samuel James Oluwafemi to jẹ ọmọ bibi Ado odo Ota ni ipinlẹ Ogun ṣalaye nipa awọn ipenija ti awọn akẹkọọ yii n dojukọ ni awujọ.

O tun mẹnuba bi iṣẹlẹ Coronavirus ati konile o gbele 2020 se fun wa ni aaye lati ṣe awọn idije kọọkan fun awọn akẹkọọ Odi ati Aditi naa.

deaf dancer