Femi Falana: Mẹ̀kúnnù gbọ́dọ̀ ṣetán láti gba ẹ̀tọ́ wọn, ìjọba ti kùnà lórí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn àti ètò aàbò
Ìjọba gbọ́dọ̀ máa da owó 'ransom' ti àwọn eèyàn bá san fún ajínigbé padà- Femi Falana
Ogbontarigi ajafẹtọ ọmọniyan ni,.Femi Falana ba BBC Yoruba sọrọ lori igbese to kan fun ijoba Naijiria ati ara ilu lori eto aabo.
O salaye lori isoro to n koju Naijiria bayii.
- Ẹgbẹ́ àwọn Oníbúrẹ́dì parí ìyanṣẹ́lódì niye owó búrẹ́dì bá lọ sókè!
- Ṣé lóòtọ́ ni agbẹjọ́rò DSS wọ ọkọ̀ "One Chance" tàwọn adigunjalè sì jí fáìlì ẹjọ 'Igboho' lọ́wọ́ rẹ̀?
- Wo iye mílíọ̀nù tí Miyetti Allah yóò máa ta màálù kan tí ìpínlẹ̀ Eko bá fòfin de ìdẹranjẹko ní gbangba
- Ìjì tó hú igi ńlá ní ìtẹ́ òkú l'Eko ba ibojì òkú 50 jẹ́, àwọn ẹbí sáré lọ w'òkú wọn
- Alálẹ̀ ló fi èmi àti Sunday Igboho pamọ́ sí àhámọ́ kí ewu le ré wa kọjá - Oba Ogboni

Oríṣun àwòrán, @Falana
Femi Falana sọrọ lori bi ijọba Naijiria se kuna lori eto aabo ati ẹtọ omoniyan.
O menuba ipa ti ijọba Buhari ati Obasanjo ko pe ijọba ologun to di alagbada ni wọn ti wọn fi maa n paṣẹ laibọwọ fun ofin ẹtọ ọmọniyan.
- Ẹ̀yin Òbí, ẹ fi ọmọbìnrin yin sílẹ̀ láti ṣe iṣẹ́ tó wù wọ́n- Deborah tó ń fi ìlú bàtá àti gángan dárà
- Wo akọrin Highlife kan tó ń kọrin bíi Lagbaja
- Ọkùnrin mẹ́wàá ló ti fipá bá mi lòpọ̀ rí, àbúrò ìyá mi lálákọ́kọ́- Oluwatobi Raji
- Wo bí wọ́n ṣe le mọ́ irú èèyàn to jẹ́ àti àìsàn tó ń ṣe ọ́ láti pasẹ̀ ‘Handwriting’ rẹ
- Ẹ gba akẹ́kọ̀ọ́ láàyè láti fi èdè abínibí kọ WAEC àti JAMB - Kola Tubosun
Falana ni aisi iṣẹ lọwọ ọdọ lo n fa iṣọro eto aabo.
O ni to ba wu aarẹ Buhari lati fopin si iṣoro ijinigbe yii, ko ni pẹ rara nitori pe agbara wa lọwọ aarẹ lati daabo bo awọn eniyan rẹ.
- Buhari, ọgá ilééṣẹ́ aṣọ́bodè rẹ́ kò mọ̀ iṣẹ́, yọ́ọ́ kúrò nípò-Sẹ́nẹ́tọ̀ Francis Fadahunsi
- Odunlade Adekola yarí lórí ìròyìn tó ní ó n bá àwọn obìnrin sùn kó tó fi wọ́n sínú fíímù rẹ̀
- Ìyàwó márùn-ún ni mo fẹ́ fún ọkọ mi, n kò sì kábàámọ̀ - Ìyá Osogbo
- Kílódé tí Sheikh Gumi fi ṣe àbẹ̀wò sí Igboho nínú gbogbo ìlú tó wà nílẹ̀ Yorùbá?
- Darandaran tó bá rúfín dída ẹran nígboro l'Ondo rugi oyin- Akeredolu yarí

Oríṣun àwòrán, others
Falana ni Ara ilu ni ẹtọ lati dide ogun nigba ti ijọba ba kuna lati pese aabo bi o ti yẹ fun wọn





