Lóòtọ́ orin mi àti Lagbaja jọra ṣùgbọ́n ìyàtọ̀ díẹ̀ wà níbẹ - Labule
Ọpọ ọmọ Naijiria, paapaa awọn to jẹ ololufẹ orin Highlife ati Afrobeats ni wọn ti n saaro orin Lagbaja nitori pe o to ọjọ melokan ti eekan akọrin naa ti gbe ara rẹ kuro lagbo orin kikọ.
Amọṣa lasiko ti Lagbaja n kọrin ni ọdọmọkunrin kekere kan nigba naa ti n wo awokọṣe rẹ to si n tọ ipasẹ irinajo rẹ.
Arakunrin naa ti ọpọ mọ si Labule ti mu ipasẹ ọna orin Lagbaja bayii ti o si jẹ pe bi o ba ti n kọrin ọpọ ti ko ba tete mọ yoo maa bere pe ṣe Lagbaja niyi abi oun kọ.
Akọṣẹmọṣẹ imọ ẹrọ Civil Engineering ni Labule ni fasiti ilu Eko ki o to tun gba ilẹ Gẹẹsi lọ lati gba imọ kun imọ ninu rẹ; ṣugbọn ifẹ orin ko fi silẹ lo fi pada wa gbe igba orin ni Naijiria.
- Iṣẹ́ àgbẹ̀ ayé àtijọ́ nira púpọ̀ ní mo ṣe ń ṣe àgbẹ̀ inú àpò
- Bí mo bá fún obìnrin lóyún báyìí, mi ò ní kọ oyún náà, ṣùgbọ́n… - Bobrisky
- Sunday Igboho ní ₦4m sí ₦3m ni ìkọ̀ọ̀kan amòfin mẹ́wàá ní Cotonou gbà láì dènà kí òun má lọ sẹ́wọ̀n
- Ìwà burúkú àti àìlẹ́kọ̀ọ́ ilé ló n tú ìgbéyàwó ká, kìí ṣe òògùn olóró
- Ìbálòpọ̀ àti nkán márùn-ùn míì tí o lè ṣé kí ará rẹ̀ fí jí pépé tó bá pé ogójì ọdún