Thyroid foundation: Eéwo ni mo kọ́kọ́ pè é àṣé gẹ̀gẹ̀ ọrùn tó lé ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ni mo ní- Adebukola Adediran
Ṣé o mọ́ irú oúnjẹ tó yẹ kí o máa jẹ́ láti dènà gẹ́gẹ́ ọrùn?- Dokita Adebambo Bankole
Wá kọ́ nípa ọ̀nà àbáyọ sí àrùn gẹ̀gẹ̀ ọrùn.
Adebukola Adediran sọ iriri rẹ pẹlu arun gẹgẹ ọrun.
Oju rẹ ri to lọwọ ẹbi, ara, ọrẹ ati iyekan lasiko to n la iṣoro yii kọja.
O ni eewo ni oun kọkọ pe e ko too wa gba ẹbọ lọwọ rẹ.
- Àwọn olùgbé Akinyele fí ẹ̀sùn ilẹ̀ gbígbà kan ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo, ìjọba Makinde ti fèsì padà
- Wo àwọn àwòràn láti ibi ètò ìsìnkú òṣèrébìnrin, Rachael Oniga
- Buhari, rọra yá owó kí Nàìjíríà má ba á kú sóko gbèsè o- Atiku Abubakar
- Wo iye ìgbà tí wọ́n ti jí akẹ́kọ̀ọ́ gbé ní Nàìjíiríà
- Ìtàn Ìjàpá àti ọbọ ni ìjọba àpapọ̀, àwọn agbófinró ń sọ nípa Igboho - Wole Soyinka

Alakoso Thyroid Foundation salaye ohun to jẹ ki oun da ajọ to n pese iranlọwọ naa fun awọn eeyan.
Se ohun ti eyan ba ti la koja ri a maa mu ni kẹdun sii fun eni to n la a kọja.

Oríṣun àwòrán, Inpho
Adebukola gba awọn eyan nimọran lati ma sẹ dọwọ bọ aarun to ba n ṣe wọn mọlẹ.
O ni o san ki a ke gbajare ki eeyan le tete ri alaanu ju ko dakẹ di oku lọ.

Dokita Bankole Adebambo salaye irufẹ ounjẹ ti o yẹ ki eeyan maa jẹ ati eyi to yẹ ko sa fun ti ko ba fe ni arun gẹgẹ ọrun.
Bakan naa lo tun sọ nipa ami ati apẹrẹ ti o ṣeeṣe lati kẹfin ni ọrun eeyan.
