Adene Oluwabukola Deborah: Bàbá mi kò kọ́kọ́ fọwọ́ sí iṣẹ́ ìlù lílù ṣùgbọ́n....

Àkọlé fídíò, Adene Oluwabukola Deborah: Bàbá mi kò kọ́kọ́ fọwọ́ sí iṣẹ́ ìlù lílù ṣùgbọ́n....

Ìdílé mi kìí ṣe Onílù rárá, ẹ̀bùn àti ìkọ́ni ni mo fi mọ̀ọ́- Adene Oluwabukola Deborah tó ń fi ìlù ṣe bẹbẹ

BBC Yoruba wa ọdọbinrin to n lu ilu bata ati gangan lọna ara kan.

Keyframe #2

Adene Oluwabukola Deborah sọ pe owo ara oun ni oun fi kọkọ ra ilu bata oun akọkọ nitori ifẹ ti oun ni si iṣẹ ilu lilu.

O sọ nipa irinajo rẹ lati ibẹrẹ ko to de ibi to ti di gbajugbaja yii

Adene Deborah menuba awọn ipenija ti oju rẹ ri.

Adene Deborah Oluwabukola

Bakan naa lo gba awọn Obi ati alagbatọ nimọran lati fi ọmọbinrin wọn sile lati se iṣẹ ti ori ran wọn.

O tun gba awọn obinrin ọdọ ni imọran lati tẹpa mọṣẹ.