Agu rí èͅwòͅn oͅdún méje he léͅyìn tó da ‘acid’ sí ara òͅréͅbìnrin rèͅ téͅlèͅ àti olólùfeͅ rèͅ

Oríṣun àwòrán, Others
Ileeͅjoͅ giga kan in Ikeja ti ran arakunrin eͅni oͅdun mejileloͅgboͅn loͅ si eͅwoͅn oͅdun meje fun eͅsun pe o da acid si ara oͅreͅbinrin reͅ teͅleͅ, Aisha Adefarati ati oͅreͅkunrin Aisha tuntun, Monsuru Ahmed.
Iroyin ni adajoͅ Oyindamola Ogala lo ni arakunrin naa jeͅbi eͅsun oniga kan to niise peͅlu sise eniyan ni ibi, paapaa, Ogbeni Agu.
Ogala ni Agu tun paroͅ lasiko igbeͅjoͅ naa pe oun koͅ lo siseͅ ibi naa loͅna ati mase gba idajoͅ to yeͅ.
Geͅgeͅ bi oͅroͅ adajoͅ naa, Agu koͅ lati mu eͅgboͅn reͅ wa si ileeͅjoͅ to soͅ pe oͅdoͅ reͅ ni oun wa loͅjoͅ ti isͅeͅleͅ yii waye.
‘’Eͅni ti woͅn fi eͅsun kan naa gbiyanju lati si ileeͅjoͅ loͅna nigba to soͅ wi pe oͅdoͅ ibatan oun lo n w ani oͅjoͅ ti isͅeͅleͅ naa waye to si koͅ lati mu eͅgboͅn reͅ oͅun wa si ileeͅjoͅ.
‘’Titi di asiko yii, agboͅn reͅ to paroͅ moͅ naa ko yoͅju si ileeͅjoͅ lati wa wi ti eͅnu reͅ.’’
Bakan naa ni eͅni ti woͅn fi eͅsun kan naa ko fi igba kankan soͅ pe oun koͅ lo da acid si ni ara, ti eyi si fihan pe o moͅoͅmoͅ gbe igbeseͅ naa ni.’’
Bakan naa ni awoͅn to da acid si lara naa wa fi ara woͅn han ni ileeͅjoͅ, ati iye ipalara to da si ara woͅn
Bi iseͅleͅ naa se waye
Oͅreͅbinrin Agu teͅleͅ ni o ma n fi iya jeͅ oun lo jeͅ ki oun fi sile leͅyin oͅdun meͅta ti awoͅn ti joͅ wa papoͅ.
Agbeͅjoro oͅreͅbinrin oͅhun ni Osu Keͅjoͅ, oͅdun 2020 ni iseͅleͅ naa waye ni ile itura Gangare Hole, Mile 12, ni ipinleͅ Eko.
Woͅn ni niise ni Agu toͅpaseͅ oͅreͅbinrin ati ololufeͅ reͅ loͅ si ile itura naa, to si da acid si woͅn lara.
Ni Adajoͅ ba ju Agu si eͅwoͅn oͅdun meje ko fi siseͅ takuntakun.
Awoͅn to wa ni ileeͅjoͅ ni arakunrin naa toͅroͅ aforiji loͅwoͅ obinrin naa ati oͅreͅbinrin reͅ teͅleͅ leͅyin to ba ileeͅjoͅ soͅroͅ tan , ti woͅn si ni o jeͅbi eͅsun naa.















