Àmì ẹ̀yẹ tí mo gbà kò sí fún èmi nìkàn bí kò ṣe fún iṣẹ́ olùkọ́ lápapọ̀ - Olùkọ́ tó pegedé jùlọ́ ní Nàìjíríà
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Nigba kan ri, awọn eeyan a maa sọ pe ọrun ni ere iṣẹ olukọ wa. Amọṣa o dabi ẹni pe awọn olukọ kan n gba ere iṣẹ tiwọn laye yii.
Ninu wọn ni Ọgbẹni Ṣolankẹ wa. Ọgbẹni Ṣolankẹ to jẹ olukọ ni ipinlẹ Ogun fun lami ẹyẹ olukọ to dantọ julọ ni lorilẹede Naijiria lọdun 2025/2026.
Nitori ogo to mu ba iṣẹ olukọ ni ipinlẹ naa, ijọba ipinlẹ Ogun, ijọba apapọ atawọn gomina miran fi ẹbun ọkọ ayọkẹlẹ ati ile ta a lọrẹ.






















