Ibi tí wóͅn ń kó oͅpoͅloͅ àwoͅn ènìyàn tó lé ní 10,000 sí rèé láti sͅewádìí ààrùn oͅpoͅloͅ

O kere tan oͅpoͅpoͅ awoͅn eniyan to le ni eͅgbeͅrun meͅwaa ni woͅn ko bamoͅ ni awoͅn Ileewosan to n toͅju awoͅn alarun oͅpoͅloͅ ni Ileͅ Geͅeͅsi.
Eleyii waye laarin òͅdun 1945 si oͅdun 1980 nigba ti imoͅ nipa eͅtoͅ oͅmoͅniyan ko I tii se koko bii asiko yii.
Nigba naa loͅhun, awoͅn dokita naa n gba oͅpoͅloͅ naa lati fi pamoͅ leͅyin ti woͅn ba ti se ayeͅwo iru aisan to n ba woͅn finran to si jasi iku woͅn.
Amoͅ ni isinyii, eto eͅtoͅ ti wa fun woͅn ti woͅn ko si lee dede ko oͅpoͅloͅ awoͅn eniyan joͅ lai gba asͅeͅ.
Bakan naa ni awoͅn onimoͅ naa fikun un pe banki ti woͅn n ko oͅpoͅloͅ naa si ti ran woͅn loͅwoͅ lati sewadii iru aisan oͅpoͅloͅ to n ba awoͅn eniyan finra nigba naa si ti aye ode oni.












