Iwo Isin, ìlú tí àwọn mùsùlùmí kìí tií ṣe okú tabí pa Màlùù ní Kwara

Àkọlé fídíò, Iwo Isin, ìlú tí wọn kìí tií pa Màlùù ní Kwara
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Awọn olugbe ilu naa kii ṣe oku tabi pa maluu pe awọn fẹ fi ṣe olu gẹgẹ bí ọrọ ti Kabiyesi ilu Iwo Isin fi to BBC News Yoruba leti.

Ọba Joshua Olutadeṣalaye pe awọn babanla ilu wo woye nigba naa pe ki wọn gbe igbesẹ naa lati lee fi alaafia ati ifọkanbalẹ lelẹ fun atolowo ati talaka nibẹ.

O ni ohun ti wọn fẹ ni pe ki o baa le maṣe si idẹyẹsi ẹda kan nitori ailowo tqbi ipa lati ra maluu tabi seto isinku bi wọn ṣe fẹ ti awọn kan a wa maa wo o gẹgẹ bi afipa ṣe.