Ǹjẹ́ ó ṣe kókó pé kí èèyàn ta ilé rẹ̀ lọ òkè òkun? Adekola Adesina sọ ìrírí rẹ̀
Lorilẹede Naijiria, ọpọ eeyan lo n gbero lati kuro ni agbegbe wọn lọ si oke okun nibi ti wọn ti lero pe nnkan yoo so eso rere fun wọn.
Ileeṣẹ BBC ba ọkan lara agba ọjẹ ninu eto ẹkọ nipinlẹ Ogun, Adekola Adesina, ẹni to ti gbe niluu Oyibo fun ọdun mẹtadinlọgbọn.
Adeshina salaye oun to ya oun lẹnu ju ni bi awọn to wa niluu Oyinbo ṣe n tiraka lati kọ si ilẹ Baba, ti wọn to si wa ni ile n ta ile wọn lati wa si ilu Oyinbo.
O ni pẹlu gbogbo iriri rẹ ni ilu Oyinbo, o ni bi ti wọn dara, to si ibi ti wọn kudiẹ kato si,
“Ilu Oyinbo ti a n sọ yii, awọn kan ti wa nibẹ fun ogoji ọdun, nigba to ba pawo, igbeaye ọhun ti ṣe ilana bi owo naa yoo ṣe lọ.
“Ẹni to ti ni ile Duolex, yara marun un, awọn ọmọ ni yara tiwọn lọtọtọ, to wa ta ile, to ko ọmọ ati iyawo, to si jẹ pe yara kan ni agbara wọn kan.”
Ọrọ pọ lẹnu Adeshina ninu fidio yii.






















