Wo bí àwọn èèyàn ṣe ṣe àjọyọ̀ ọdún Kérésì ní Nàìjíríà àti káàkiri àgbáyé

Ajọdun Keresimesi waye kaakiri agbaye lati sami ayajọ ọjọ ibi Jesu Kristi.

Ajọdun Keresimesi jẹ ọkan pataki ninu awọn ajọdun ti awọn ẹlẹsin Kristẹni kii fi ṣere rara.

Awọn ọlọdun Keresi kan n luwẹ lorilẹede Spain

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn ọlọdun Keresi kan n luwẹ lorilẹede Spain
Awọn ẹlẹsin Kristẹni ni Kashmir lorilẹede Pakistan pẹlu dara pọ mọ ọdun Keresimesi.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn ẹlẹsin Kristẹni ni Kashmir lorilẹede Pakistan pẹlu dara pọ mọ ọdun Keresimesi.
Eeyan kan n wo aworan baba keresi

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Eeyan kan n wo aworan baba keresi
Awọn olujọsin kan ni ilu Tundun Biri nibi ti awọn ologun NAijiria ti ṣe aṣiṣe ju ado oloro to pa ọpọlọpọ laipẹ yii
Àkọlé àwòrán, Awọn olujọsin kan ninu ṣọọsi lọjọ keresimesi ni ilu Tundun Biri nibi ti awọn ologun Naijiria ti ṣe aṣiṣe ju ado oloro to pa ọpọlọpọ laipẹ yii.
Awọn Kiristẹni ko ara jọ pọ lati ṣe ajọdun Keresimesi ni ibudo igbafẹ kan ni orilẹede Philippines.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn Kiristẹni ko ara jọ pọ lati ṣe ajọdun Keresimesi ni ibudo igbafẹ kan ni orilẹede Philippines.
Awọn obinrin kan ninu ile ijọsin lati jọsin fun ayajọ ọdun keresimesi ni orilẹede Pakistan.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Awọn obinrin kan ninu ile ijọsin lati jọsin fun ayajọ ọdun keresimesi ni orilẹede Pakistan.
Awọn Kristẹni ati Musulumi ko ara jọ pọ lati sayajọ ọdun keresimesi ni ile ijọsin kan ni Tundun Biri ni ipinlẹ Kaduna
Àkọlé àwòrán, Awọn Kristẹni ati Musulumi ko ara jọ pọ lati sayajọ ọdun keresimesi ni ile ijọsin kan ni Tundun Biri ni ipinlẹ Kaduna