Queen Elizabeth II: Wo ọ̀pọ́ àwòrán ìgbà tí Ọbabìnrin ti kópa nínú eré ìdárayá

BBC ṣe akọjọpọ awọn akoko ti ỌbabinrinElizabeth kopa ninu ere idaraya.

Queen Elizabeth

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ẹṣin akọkọ ti wọn fun ỌbabinrinElizabeth ree, orukọ ẹṣin naa ni Peggy, to jẹ ẹranko ọdun mẹri. Igba akọkọ ti yoo so gun ẹṣin naa ree lọdun 1952.
Margaret

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth fẹran ẹṣin pupọ nigba aye rẹ, o si maa n yọju sibi awọn ayẹyẹ. Asiko to yọju sibi idije ere ẹṣin kan ree pẹlu aburo rẹ, Princess Margaret.
Kraliça və and Althea Gibson

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ni 1957, Ọbabinrin Elizabeth gbe ami ami ẹyẹ Wimbledon fun Althea Gibson, to jẹ ọkunrin alawọmdudu tii yoo ami ẹyẹ SW19.
Jack Burkitt-

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọdun meji lẹyin naa, Ọbabinrin Elizabeth yọju sibi aṣekagba ifẹsẹwọnsẹ FA Cup nibi ti Nottinham Forest ti din dundu iya fun Luton pẹlu ami ayo 2-1, to si gbe ami ẹyẹ fun Jack Burkitt.
Kraliça 1966
Àkọlé àwòrán, Papa iṣere Wembly ni 1966, Elizabeth fun agbabọọlu Bobby Moore ni ami ẹyẹ ife ẹyẹ agbaye lẹyin ti wọn na West Germany ni ami ayo 4-2
Ọbabinrin Elizabeth ṣe ayẹyẹ 'Silver Jubilee" rẹ ni Wimbledon lasiko ifẹsẹwọnsẹ awọn obinrin ninu eyii ti Virginia Wade ti jawe olubori

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth ṣe ayẹyẹ 'Silver Jubilee" rẹ ni Wimbledon lasiko ifẹsẹwọnsẹ awọn obinrin ninu eyii ti Virginia Wade ti jawe olubori
Ọbabinrin Elizabeth wa nibi aṣekagba idije Euro 96 ni papa iṣere Wmbly laarin Germany ati Czech Republic, Germany lo bori idije naa

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth wa nibi aṣekagba idije Euro 96 ni papa iṣere Wmbly laarin Germany ati Czech Republic, Germany lo bori idije naa
Ayẹyẹ iṣide Commonwealth to waye ni manchester ree lọdun 2002 pẹlu David Beckham ati Kirsty Howard

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ayẹyẹ iṣide Commonwealth to waye ni manchester ree lọdun 2002 pẹlu David Beckham ati Kirsty Howard
Ọbabinrin Elizabeth lo ṣi idije hockey ni Slovenia lọdun 2008 nibi ti Guildford Flames ati Aquacity Poprad ti koju ara wọn

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth lo ṣi idije hockey ni Slovenia lọdun 2008 nibi ti Guildford Flames ati Aquacity Poprad ti koju ara wọn
Elizabeth tun kopa nibi iṣide ayẹyẹ Olympic nibi to ti farahan ninu fiimu kan pẹlu James Bond (Daniel Craig)

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Elizabeth tun kopa nibi iṣide ayẹyẹ Olympic nibi to ti farahan ninu fiimu kan pẹlu James Bond (Daniel Craig)
Kraliça Tanni Grey-Thompson-la

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Kraliça 2012-ci ildə paralimpiya oyunlarının da rəsmi açılışını etdi və 11 dəfə paralimpiya çempiyonu olmuş Baroness Tanni Grey-Thompson-la görüşdü.
Ọbabinrin Elizabeth naa lo ṣide eto 2012 Paralympics nibi to ti pade ẹni to gab ife ẹyẹ eto nigba mọkanla, iyẹn Baroness Tanni Grey-Thompson

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth naa lo ṣide eto 2012 Paralympics nibi to ti pade ẹni to gab ife ẹyẹ eto nigba mọkanla, iyẹn Baroness Tanni Grey-Thompson
Ẹṣin Ọbabinrin Elizabeth, Estimate, kopa ninu idije ere sisa fun awọn lọdun 2013, o si jẹ igab akọkọ ti ẹṣin ọba to wa lori oye yoo gba ife ẹyẹ idije naa lati ọdun mẹ́tàdínláàdọ́fà sẹyin

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ẹṣin Ọbabinrin Elizabeth, Estimate, kopa ninu idije ere sisa fun awọn lọdun 2013, o si jẹ igab akọkọ ti ẹṣin ọba to wa lori oye yoo gba ife ẹyẹ idije naa lati ọdun mẹ́tàdínláàdọ́fà sẹyin
Ọbabinrin Elizabeth ba Bryan Habana lati South Africa ati Henry Speight sọrọ ṣaaju idije ife ẹyẹ agbaye Rugby lọdun 2015

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ọbabinrin Elizabeth ba Bryan Habana lati South Africa ati Henry Speight sọrọ ṣaaju idije ife ẹyẹ agbaye Rugby lọdun 2015
The Queen and Ryan Moore

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ryan Moore ba Queen Elizabeth sọrọ lọdun 2016
Aafin Burkinham ni Queen Elizabeth ti gbalejo awọn to gba anmi ẹyẹ Rio Olympics and Paralympics lọdun 2016 kan naa, ara awọn to wa nibẹ ni Nicola Adams

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Aafin Burkinham ni Queen Elizabeth ti gbalejo awọn to gba anmi ẹyẹ Rio Olympics and Paralympics lọdun 2016 kan naa, ara awọn to wa nibẹ ni Nicola Adams
Ni 2017, Queen Elizabeth yọju sibi idije Royal Ascot

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ni 2017, Queen Elizabeth yọju sibi idije Royal Ascot
Queen Elizabeth yọju si Royal Ascot to waye lọdun 2021

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Queen Elizabeth yọju si Royal Ascot to waye lọdun 2021
Ninu oṣu Kẹwaa, ọdun 2021, Queen Elizabeth wa ayẹyẹ iṣide to ṣaaaju Commonwealth Games ti Birmingham lọdun yii

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Ninu oṣu Kẹwaa, ọdun 2021, Queen Elizabeth wa ayẹyẹ iṣide to ṣaaaju Commonwealth Games ti Birmingham lọdun yii