Osun Governorship Election Result 2022: Báyìí ni èsì ìdìbò Gómìnà ìpínlẹ̀ Osun ṣe ń jáde

Nibayii, esi idibo ti n jade sita eyi to sọ iye ibo ti oludije kọọkan ni lawọn ibudo idibo ti wọn ti dibo fun wọn ni ipinlẹ Osun.
Awọn nkan tẹẹ le ri lori maapu yii ni orukọ awọ́n to n le waju ni ijọba ibilẹ kọọkan titi ajọ INEC yoo fi kede apapọ gbogbo onka idibo ti ẹni kọọkan ni.
Gbogbo bi ajọ eleto idibo ṣe n kede iye ibo ti onikaluku ni la n tẹẹ sinu tabili to n ṣe iṣiro awọn esi naa to si n gbe e wa sorii maapu yii.
Torinaa, ẹ fi atọna ika yin (Cursor) rin kaakiri ori maapu yii, ẹ o maa ri gbogbo esi idibo naa.
Bi ẹ ṣe lee wo esi idibo
Sun atọna (cursor) ori foonu tabi ẹrọ kọmputa rẹ kaakiri ori atẹ to wa nisalẹ yii, yoo ṣafihan ijọba ibilẹ kọọkan ati esi idibo ibẹ.










