Ọmọ ilẹ̀ China tó fìyàjẹ ọmọ Kenya dèèrò ilé ẹjọ́

Aworan ọmọ ilẹ China to na ọmọ China

Oríṣun àwòrán, Twitter/citizentvkenya

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 2

Ara me riri,mo ri ori oloogbo latẹ.

Gbolohun eemọ re lo n jade lati ẹnu awọn ọmọ orilẹ-ede Kenya lori bi ọmọ ilẹ China kan ti ṣe to ẹgba sidi ọmọọṣẹ rẹ kan to jẹ ọmọ orilẹ-ede Kenya tori pe o pẹ de ibiiṣẹ.

Ni ile ounjẹ kan ti o jẹ t'awọn ọmọ ilẹ China ọhun, iyẹn Chez Wou Restaurant to ni agbegbe Kileleshwa l'olu ilu Kenya, Nairobi ni iṣẹlẹ naa ti waye.

Niṣe ni oju opo ayelujara gbana lẹyin ti ilẹeṣẹ amohunmaworan kan K24 TV fi fọnran fidio han nibi ti ọkunrin, ọmọ China kan ti n na ọmọ Kenya kan lẹgba.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Lẹyin awuyewuye ti fidio yi mu wa, ileeṣẹ ọlọpaa ni Kenya fi ọrọ sita pe awọn ti mu awọn ọmọ ilẹ China mẹrin ti wọn n ṣiṣẹ ni ile ọunjẹ naa.

Aworan awọn ọmọ China ni ile ẹjọ ni Kenya

Oríṣun àwòrán, KTV

Gẹgẹ bi ohun ti wọn fi sita,eniyan kan pere ninu wọn lo ni iwe aṣẹ to gba laaye lati ma ṣiṣẹ ni Kenya.

Bakan naa ni wọn sọ pe awọn ọmọ Kenya mẹjọ to n ṣiṣẹ nibẹ l'awọn n wadi ọrọ lẹnu wọn.

Wayi o,ileeṣẹ orileede China ni Kenya ti ni digbi lawọn wa lẹyin awọn alaṣẹ nipa wiwadi ẹni to ba tasẹ agẹrẹ sofin.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Ẹ gbe lọ si Wuhan ni!

Orisirisi ọrọ lawọn ọmọ Kenya ti n sọ nipa iṣẹlẹ yi, ti wọn si ni ko da ki eeyan jẹ ẹru ni ilẹ baba rẹ.

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Skip X post, 4

End of X post, 4

@KiplangatLedama ni ti ẹ sọ pe ki wọn mu ẹni to hu iru iwa yi lọ si ilu Wuhan ti Coronavirus ti n ba awọn eeyan finra.

Skip X post, 5
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 5