BUSA19: Bí ètò ìgbéyàwó ààrẹ Buhari kò bá ṣe lọ rèé -àwọn ènìyàn Nàíjíríà

Buhari

Oríṣun àwòrán, @others

Àkọlé àwòrán, Lẹyin to ti hande pe iroyin ẹlẹjẹ ni igbeyawo aarẹ Buhari ti awọn eeyan n pariwo lori ayelujara; sibẹ ọpọ aworan to panilẹrin fun ipalẹmọ lo kun ayelujara bayii
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 5

Oriṣiiriṣi aworan ati akọle to pani lẹrin lo ti kun ori ayelujara ni eyi ti awọn eniyan fi n ṣeto ipalẹmọ igbeyawo ofege ti wọn ni o yẹ ko waye laarin Aarẹ Buhari ati Hajiya Sadiya Umar Farouq.

Ṣaaju ni iroyin ẹlẹjẹ ti gba ori ayelujara pe eto igbeyawo naa yoo waye laarin minista tuntun fun Abojuto lori ọrọ Ijamba ati Igbayegbadun ọmọniyan lorilẹ-ede ati aarẹ Naijiria.

Ṣugbọn lẹyin pe gbogbo nkan to n jade lati ọdọ awọn ti ọrọ kan fihan pe irọ to jina si ootọ ni iroyin ẹlẹjẹ naa; sibẹsibẹ ayelujara ti kun fun oriṣiriṣi aworan ati akọle to fihan pe apanilẹrin ni awọn eniyan Naijiria.

Wo diẹ lara akọle ati awọn aworan apanilẹrin to wa lori ayelujara:

Lóòni ni ayẹyẹ ìgbéyàwó ààrẹ Buhari ni'lù Abuja ni eyi ti ero ti n de si Abuja:

Tweet

Oríṣun àwòrán, Ogundamisi

Àkọlé àwòrán, Awọ asọ oni ni Pepper-Dem Green àti Wailers white

Ní bayìí àwọn èèkan ilú, àwọn olóṣèlú àwọn ọmọ Naijiria jákejádo lo ti si nń gúnlẹ̀ sí ìlú Abuja.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Kayodebarkre

Àkọlé àwòrán, Ebora owu naa ti de ibi ayẹyẹ

Nínú ètò ti yóò wáye ni mọsàlási Jimoh nílùú Abuja lásìkò irún Jimoh toni ní wọn ti maa so wọn pọ.

Tweet

Oríṣun àwòrán, MrLekan Adigun

Àkọlé àwòrán, Awon eekan ninu PDP naa de bẹ

Láìpẹ́ yìí ìròyìn kan déedé bẹ̀rẹ̀ si ni ja rainrain lójú opó twitter pe ààrẹ orilẹ̀-èdè Nàijíríà Muhammadu Buhari yóò fẹ́ ìyàwó tuntun sáàfin.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Ayourb

Àkọlé àwòrán, Awọn aarẹ orile-ede naa ti de silu Abuja

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ìròyìn yìí ko fẹ́sẹ̀ múlẹ, ti ko si si oun a ri gbámu kankan níbẹ̀, ọ̀pọ ọmọ Naijiria ti pari bi gbogbo ǹkan yóò ṣe lọ leto leto.

Tweet

Oríṣun àwòrán, @ogbeni_Skrtel twitter

Àkọlé àwòrán, Arakunrin Ondo àti awọn gomina ilẹ Yoruba

Oko iyawo ti n mura bayii:

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

Láti ori ìwé ìpè àlejo tó si mo adari ètò ounjé, àti adari ounjẹ ní wọ́n ti fóju wọ́n han bàyìí:

Tweet

Oríṣun àwòrán, QOlakul

Àkọlé àwòrán, Oko iyawo ti wọ agbo
Tweet

Oríṣun àwòrán, Imaam Shams

Àkọlé àwòrán, Eto iyawo ti bẹ̀rẹ̀ ni pẹrẹwu

Nínú ètò ti yóò wáye ni mọsàlási Jimoh nílùú Abuja lásìkò irún Jimoh toni ní wọn ti maa so wọn pọ.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Osi_Suave

Àkọlé àwòrán, Awon olorin ati osere tiata

Awọn alejo miran ti awọn eniyan n ṣe awada pe o ti de sibi eto naa ni:

Tweet

Oríṣun àwòrán, Iwara139

Àkọlé àwòrán, Bobbriski lo wọ pepper-dem green yii oo
Tweet

Oríṣun àwòrán, Optimistic-Ade

Àkọlé àwòrán, Abubakar Atiku bawọn n dáwọ idunnu nibẹ
Tweet

Oríṣun àwòrán, Hassan winger

Àkọlé àwòrán, Dino ati àwọn ẹmẹwaa rẹ sááju ọjọ igbeyawo lọ ki Baba Buhari

Ayẹyẹ yiìí ko yọ Trump silẹ bi o se fí ohun ránsẹ pé òun ko ni le raye wá.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Ayo Akanji

Àkọlé àwòrán, Em aa binu si mi pe mi o ni le yóju, ọ̀rọ̀ Turkey ati Kurdish lo fàá

Àwọn tí ìbàdan, ní ìpínlẹ̀ Oyo, Porthacourt àti Imo

Tweet

Oríṣun àwòrán, Tajudeen Olajide

Àkọlé àwòrán, Micra lawọn ara Ibadan yoo gbe de Abuja lati yẹ ọkọ iyawo sí
tweet

Oríṣun àwòrán, H cookey

Àkọlé àwòrán, Awon tori omi o gbẹ́yìn

Ọkọ ìyàwọ ti de nínú ọkọ bọginin rẹ̀ ti àwọn alábarin àti olólùfẹ́ rẹ̀ si n wọ́ tẹ̀le.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Kola Stephen

Àkọlé àwòrán, Awon ti pota ree ni Garaji ọkọ

Wọn ni asọ ti yóò lé wọ òde ìgbéyawo náà ni Pepper-dem àtio wailers White

Ìyá Micho àti awọn alágbàse míràn lo soju nibi iyẹyẹ náà

tweet

Oríṣun àwòrán, AbiolaGenus8

Àkọlé àwòrán, Awọn olunjẹ ti bẹ̀rẹ̀ si ni in ounjẹ
Tweet

Oríṣun àwòrán, Johannx

Àkọlé àwòrán, Mr JAG naa wa lara awon kongila olounje
Tweet

Oríṣun àwòrán, Bolatito

Àkọlé àwòrán, Awon ounjẹ to joju ni gbese
Tweet

Oríṣun àwòrán, Bolabelyncon

Àkọlé àwòrán, Mo gbo moya ti fẹ pari oujẹ inawo

Alaga idúro fú ìdíle ayẹyẹ igbeyawo náà ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni pẹrẹwu

Tweet

Oríṣun àwòrán, Modabba

Àkọlé àwòrán, Ogbeni Raufu ti bẹ̀rẹ̀ isẹ́
Tweet

Oríṣun àwòrán, Bababosso

Àkọlé àwòrán, Won ti bẹ̀rẹ̀ sinu gbọ́wọ́ ijo gẹngẹ

Gbogbo elere fún ayẹyẹ naa ooo

Tweet

Oríṣun àwòrán, Lucasscot_101

Àkọlé àwòrán, Igbakeji àarẹ ni Gbogbo elere nibi ode yii
Tweet

Oríṣun àwòrán, Optimistic_Ade

Àkọlé àwòrán, Ààrẹ aná ni Naijiria, tí n mura silẹ fun ayẹyẹ yìí
Tweet

Oríṣun àwòrán, HelloMilez

Àkọlé àwòrán, Awon Orẹ Oko

Awọn asọna fun ayẹyẹ igbeyawo naa

tweet

Oríṣun àwòrán, @Uwayasi

Àkọlé àwòrán, Awon asona ti yóò ma ran alejo lọ́wọ́ nibi ayẹyẹ yii

Minisita fun ere idaraya tẹlẹ ni odẹ aperin ti yóò pese gbogbẹlan ti wan nilo.

Tweet

Oríṣun àwòrán, Lugard Fredo

Àkọlé àwòrán, Minisita fun ere idaraya tẹlẹ ni odẹ aperin ti yóò pese gbogbẹlan ti wan nilo

Awọn ọmọ Naijiria ba fi fidio bi igbeyawo naa ṣe lọ sita pe:

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

tweet

Oríṣun àwòrán, BadMAnLade

Àkọlé àwòrán, Awon mogbọ moya rèé ti wan mu iwe iwole dani

E seun ti ẹ wa, ẹbun àmurele rèé fun gbogbo awọn ti wan wa fun ayẹyẹ igbéyawo yìí:

Skip X post, 3
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 3

Tweet

Oríṣun àwòrán, #sirtunji

Àkọlé àwòrán, Awọn ẹbun ti wọ́n pin fun alejo

Kini o ti ṣẹlẹ sẹyin?

Èmi kò fẹ́ Aàrẹ Buhari o- Sadiya Umar Farouq

Lati bii ọjọ mẹta kan ni iroyin ti gba ori ayelujara kan pe Aarẹ Muhammadu Buhari to n tukọ Naijiria fẹ gbe iyawo miran le Ayisha aya rẹ.

Nigba ti Ileeṣẹ BBC kan si awọn ti ọrọ kan naa ni wọn fidiẹ mulẹ pe iroyin ẹlẹjẹ ni o.

Sadiya

Oríṣun àwòrán, @Sadiya

Àkọlé àwòrán, Ẹ yee parọ mọ mi o! Emi ko fẹ aarẹ Buhari -Sadiya Umar Farouq

Eni ti a ba sọrọ ni ọdọ Hajiya Sadiya Umar Farouq to jẹ minista tuntun tijọba Buhari yan fun ileeṣẹ ijọba apapọ tuntun ni Abuja ni Hajiya Sadiya wa ni Geneva bayii ni eyi to fihan pe irọ pata to jina si otitọ ni ọrọ naa.

Oṣu kẹjọ, Ọdun 2019 lo di Minisita fun Abojuto lori ọrọ Ijamba ati Igbayegbadun ọmọniyan lorilẹ-ede yii Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa àwọn obìnrin méje ti Buhari fẹ́ yàn sípò minista.

Kini ootọ inu Fidio ti Ayisha ti n binu to n tan lori ayelujara bayii?

Nigba ti BBC bere nipa fidio to ṣafihan Ayisha to n binu lori ayelujara, pe:

" ........ Kini o de ti o fi n ti lẹkun?....... A ni o le nigba awọn ọmọ ogun ni Aso Rock yatọ si igba ọlọpaa to n ṣọ wa.....O to gẹ........ awọn oponu dede...."

Bakan naa ni ẹni ti BBC ba sọrọ nile iṣẹ aarẹ to ni ki a ma darukọ oun ṣalaye pe irọ to jina si ootọ ni pe wọn dé aya aarẹ Buhari, Aisha mọ́lé ninu Aso Rock.

Ọkan lara awọn oluranlọwọ Aisha Buhari ti BBC ba sọrọ naa ṣalaye pe fidio naa ti pẹ.

O ni fidio naa kii ṣe ohun to n ṣẹlẹ bayii rara.

Ati pe irọ ni ohun ti wọn n sọ lori ayelujara pe Aisha de pẹlu ibinu si Aso Rock ni ana.

Nipari o ni Ayisha Buhari ti lọ si London lati bii oṣu mẹrin sẹyin ni eyi ti o ni nitootọ ni irinajo yii ti n fa wahala diẹdiẹ laarin aarẹ Buhari ati Aisha aya rẹ.

Sadiya Umar Farouq ti wọn pori ẹ ninu ọrọ yii paapaa ni oun ko si ni Naijiria lasiko yii nitori o ti ba ọrọ bi yoo ṣe dara lọ si Geneva lati bii ọjọ melo sẹyin.

Skip X post, 4
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 4

Skip X post, 5

End of X post, 5