IRememberWhen: Àràmànda ni ǹkan ti ẹlọmiran ń ránti
Igbàkan o lọ bi òréré, àkisà náà ti lògbà rí, gbogbo èniyàn lo ti ni àsìkò kan tàbi omíràn ti wọ́n ko le gbàgbé láilái.

Ní ọjọ oni, ǹkan tí àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ ni mímú ìránti wọ́n pàda si ìgbà àtẹyin wá. Lara ǹkan ti àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ n rèé lójú òpó twitter wọ́n.

Bí àwọn kan ṣe ń sọ nípa bi ìmẹẹrọ àti ìbanisọrọ̀ ṣe rí nbẹ́ẹ̀ ni àwọn míràn ń ránti àwọn àjálu to ti wáye sẹ́yìn

Oríṣun àwòrán, Huw Evans picture agency
Ṣe ẹyin naa ba wọn la eekana Gowon tyabi ẹ jẹ iru bisikii yii?


Ọpọ awọn ọdọ asiko yii ni wọn ko jẹgba ri tori pe wọn fọ́ ẹyin lantani oke yii; ṣugbọn awa kan jẹ ẹgba ati igbaju olooyi tori pe ẹyin lantaani oke yii jabọ lọwọ wa.














