Jẹẹsí Eagles: Bí wọ́n ṣe ṣíi ní London náà ló tán lórí igbá

Àwọn tí ó fẹ́ ra jẹsí Naijiria

Oríṣun àwòrán, @conroy_bumpus/Twitter

Àkọlé àwòrán, Ní wákàtí péréte lẹ́yìntí wọn ṣí jẹsí náà ni wọn ra gbogbo rẹ̀ tan
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Àwọn ọmọ orílẹ̀-ede Naijiria ati àwọn aláwọ̀ funfun, ti ya bo iléeṣẹ́ Nike tí ó ṣe aṣọ egbẹ́ agbáọ́ọ̀lù Naijria, ní kété tí wọn ṣí aṣọ náà ní iléeṣẹ́ wọn tí ó wà ní London.

Agbaboolu to wo jeesi
Àkọlé àwòrán, Jẹẹsi náà dùn lati wo lójú

A tí lẹ̀ gbọ́ pé, èrò tí ó wá sí ṣọ́ọ́bù Nike náà láti ra jẹẹ́sí ní ìgbaradì fun ìdíje ife àgbáyé pọ̀ tó bẹ̀ẹ̀, tí wọ́n tò láti àdúgbò kan sí òmíran.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Iléesẹ́ Nike sọ lójú òpó ìkànsíraẹni Twitter wọn pé lóótọ́ ni ajé bu igbá jẹ.

Skip X post, 1
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 1

A gbọ́ pé, aago mẹ́jọ àárọ̀ ni wọn ṣí jẹẹsí náà, ní wákàtí péréte lẹ́yìn náà, ni Nike ba sọ pé wọn ti ra gbogbo jẹẹsí tí ó wà nílẹ̀ tán.

Skip X post, 2
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post, 2

Àkọlé fídíò, 'Obìnrin tí kó ba fẹ́ òṣìṣẹ́ Mọ́ṣúárì, ìpinu rẹ̀ mẹ́hẹ'