Wizkid Vs Onochie: Ǹkan tó fàjà láàrín Lauretta Onochie àti Wizkid gan rèé

Ariwo lo gborí ayélujara kan lówùrọ̀ òní lórí ìjà láàrín olorin Ayo Ibrahim Balogun tí gbogbo èníyàn mọ̀ sí Wizkid àti amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ààrẹ Muhammadu Buhari Lauretta Onochie.
Wọ́n fi ìjà pẹ́ẹ́ta lẹ́yìn ti ààrẹ Muhammadu kó ọ̀rọ̀ ìkíni si ààrẹ ilẹ̀ Amẹríkà Donald Trump ni kété tó kéde pé òun ni ààrùn Coronavirus lọ́jọ́ Ẹti tó kọ́jà òun gbà àdúra fún ìmúláradá tó yá kánmọ́ fun un.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 1
Tí Ayo Ibrahim Balogun (Wizkid) náà sì fún ààrẹ Buhari lesì pada pé
'' kò sí ǹkan tó kan ọ pẹ̀lú ààrẹ Donald Trump
Baba arúgbó! àwọn SARS ń pa àwọn
ọ̀dọ́ Nàìjíríà lójoojújmọ́! Wá ǹkan ṣe si i!
kò sí bí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ Amẹríkà ṣe kàn ọ́
gbájúmọ́ orílẹ̀-èdè rẹ̀.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 2
Báyiìí ni ọ̀rọ̀ náà ti bẹ̀rẹ̀ tí àgbẹnusọ ààrẹ Muhammadu Buhari, Lauretta Onochie si fún Wizkid lésì pé ìwà àilẹ́kọ̀ọ́ ni kí ènìyàn pe ẹni kẹ́ni ní arúgbo. Ṣùgbọ́n ìwà àti ìṣesí Ayo Balogun láti máá pe ààrẹ ní arugbo, èyí kìí ṣe ǹkan to bójúmu rárá.
- Ìdí ọlà mí mọ́, bí mo sì ta gbogbo dúkìá mi, kò ní kí òṣì tán ní Nàíjíríà - Dino Melaye
- Ìdájọ́ ẹ̀wòn gbére kò ní kí Wòlíì Sotitobire má lọ sí ilèẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn - Agbẹjọ́rò Pásítọ̀ Alfa Babatunde
- Sotitobire àti àwọn wòlíì ọmọ Nàìjíríà míràn tó ti lọ sẹ́wọ̀n nítorí ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn
- ENDSARS: Ẹ̀yin ọmọ Nàìjíríà, ẹ ṣè ìrànwọ́ irinṣẹ́ fáwọn ọlọ́pàá- Naira Marley bẹ̀bẹ̀
- Dapo Abiodun yan Laycon ní aṣojú pẹ̀lú ẹ̀bún ₦5m àti ilé oníyàrá mẹ́ta
Ó máa ń fi ara rẹ̀ han bí aláìlóyé, ẹni ti kò ní ìmọ̀lára ọmọlakeji rẹ̀ tó sì máa n hùwà bi ọmọde.
Bóya tó ba dàgbà, yóò kọ́ bi wọ́n ṣe ń bọ̀wọ̀ fágbà.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 3
Lẹ́yìn èyí ni Wizkid náà tún dá àgbẹnusọ ààrẹ Buhari lohun pé ẹni tó ti pé ọdún mẹtàdínlọ́gọ́rin kìí ṣe ọmọde mọ, obìnrin ní ọ òbí sì ní ọ pẹ̀lú, àwọn ọlọpàá SARS ń pa àwọn ọmọ ọlọmọ lójoojúmọ́.
Ṣé ńkan tí o rí sọ ni pé mo pé ààrẹ ni arúgbó? Ojú gbà mi ti fún un! Baba ni mi, kò sì sí ǹkan tí ọjọ́ orí ní ṣe pẹ̀lú kí ènìyàn máa bere fún ìjọba tó dára ní orílẹ̀èdè rẹ!
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 4
Kíní àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ?
Ẹ̀wẹ̀ olúkúlùkù ló ń sọ èrò tíwọn lórí ọ̀rọ̀ náà lórí ayélujara, bí àwọn kan ṣe wà lẹ́yìn agbẹnusọ ààrẹ Buhari ní àwọn míràn ni ǹkan ti Ayo Balogun sọ kò tìí pọ̀jù ẹnu rẹ̀ lọ.
Nínú àwọn tó wà lẹ́yìn àgbẹnusọ Buhari tó sì bẹnu àtẹ́ lu ọ̀rọ̀ Wizkid ni @Esta123 tó ni nítorí ọ̀rọ̀ ti Wikzkid sọ òun ti fún ni orúkọ tuntun
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 5
Bákàn náà ni ẹlòmíràn ní ó yẹ ki Wizkid mọ àgbékalẹ̀ ọ̀rọ̀ ju bi o ṣe sọ yìí lọ, "yéé ṣe bi ọmọdé".
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 6

End of X post, 7

End of X post, 8

End of X post, 9
Àwọn ẹlòmíràn lórí àtẹjíṣẹ́ twitter náà yari fún àgbẹnusọ ààrẹ Buhari pé, òun paàápàá tó n sọ̀rọ̀, ṣebí ó ti fi ìgbà kan pe ènìyàn ni arúgbó rí.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 10
Wọ́n fi kún un pé ìbọ̀wọ̀ fágbà ti Onochie ń pariwo yìí náà ló sọ orílẹ̀ èdè yìí di ǹkan tó dà lónìí.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 11
Elòmíràn lára àwọn tó wà lẹyin Wizkid ṣàlàyé pé àgàbàgebè àwọn ọmọ Nàìjíríà ti pọ̀jù, ó ní tí Wizkid bá kọ láti sọ̀rọ̀ àwọn náà yóò fẹ̀sùn kan pé kò sọ̀rọ̀.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post, 12