World Cup 2018: Ijàkàdì kọ́, Ipele àkọ́kọ́ nínú ìdíje pari!

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Rẹfiiri Milorad Mazic fun Johan Mojica Colombia ni kaadi YeloÈsì ìdíje ti gba omi ẹkún lójú ọpọlọpọ agbábọ́ọ̀lù atawọn olólùfẹ́ wọn ni Russia 2018.
Àrà ọ̀tọ̀ ni ìdíje eré bọ́ọ̀lù FIFA 2018 ń jásí lọ́tẹ̀ yìí.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Senegal naa ja ninu idije Russia 2018Àwọn ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù kọọkan ń ṣe ju bí àwọn èrò ṣe rò lọ nigba ti àwọn miiran n já wálẹ̀ láìròtẹ́lẹ̀. Ìdíje bọọlu ti gba iṣiro lọ́tẹ̀ yìí.
Àkọlé àwòrán, Croatia gbo ewúro sójú NàìjíríàÌdíje FIFA 2018 ti gbé ojú àwọn agbabọọlu tuntun síta gbàgede.
Àkọlé àwòrán, Mexico ni Odò kékeré ti Germany fojú di, wọn ṣíná fún àwọn Germany to gba ife gbẹyin
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Germany to gba ife ẹyẹ gbẹyin náà kógbá wọlé ni Russia 2018
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Mertens náà kò gbẹ́yìn nínú ìdíje tòní bí o se ran Belgium lọ́wọ́ láti jáwe olúboriÀkọlé àwòrán, Croatia gbo ewúro sójú Argentina ní World Cup 2018
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Gbogbo agbára ni ọrọ bọọlu gba bayii, nilẹ tabi lojú ofurufuBọọlu gbígbá ti di, 'A ju ara wa lọ; ìjàkadì kọ́'!

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Gbigba bọọlu sáwọ̀n kọja ààwọ̀ dudu tabi pupaIkú to n pa ojúgbà ẹni, òwe nla lo n pa fun ni.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, 'ọ̀rẹ́ lo yẹ kí a máa ṣe; bóyá wọ́n nà wá tàbí a nà wọ́n'
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Iṣẹ agbara, ọgbọ́n ati ìṣirò ni bọọlu gbigba bayii
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Ọmọ to ba ṣiṣẹ́ déédé yẹ kò lasiko ayọ̀ kíkúnIpele akọkọ ninu idije ife ẹyẹ agbaye Russia 2018 ti pari.
Awọn orilẹ-ede kan to kogba wọle nigba ti awọn to yege n tẹsiwaju ninu ipele Komẹsẹ- o- yọ-danu.
Àkọlé fídíò, Onímọ̀ ọrọ̀ ajé: Àfíkún ìsúná táwọn asòfin se b‘ófin muÀwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Àkọlé fídíò, 'Lórí ìgbéyàwó mi, ẹ̀ ṣáà jẹ́ kó wà báyìí'