Sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ikọ̀ tí yóò gba ife ẹ̀yẹ àgbáyé 2018 pẹ̀lú eré ìdárayá tuntun ti BBC

Ǹ jẹ́ o leè sọ àsọtẹ́lẹ̀ tó dájú nípa ikọ̀ tí yóò borí ní Russia 2018? Ikọ̀ agbábọ́ọ́lù wo ni yóò la ìsọ̀rí àkọ́kọ́ kọjá? Se àsọtẹ́lẹ̀ rẹ, kó o sì pin-in pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn nípa lílo eré ìdárayá tuntun ti BBC.

Jọ̀wọ́ mú àgbéga bá ojú òpó tó ń gbà wọlé láti ka àwọn ìròyìn yìí
Illustration of World Cup fans
BBC