Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Mo gbọ pe ijọba ipinlẹ ondo ti wo gbagede iranti ti wọn kọ fun iranti awọn to ku ninu ikọlu to waye ni Owo lọdun 2022.
Ki lo de e?
Idi ni BBC Yoruba fi ṣabẹwo siluu Owo lati ṣewadii ohun to ṣẹlẹ gan-an.
Ohun ti a ba bọ wa lori ikanni BBC.Com/Yoruba
'''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ki lo n fa ija laarin awọn ọmọ gomina ipinlẹ Oyo tẹlẹ ri, Oloogbe Adebayo Alao-Akala?
O gbẹnutan o, ija naa le debi wi pe awọn kan ni ki wọn hu oku rẹ bayii
BBC Yoruba ṣe iwadii lori ọrọ naa
Kan soju opo wa fun abọ iwadii ti a ṣe lori ọrọ ọhun
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
B'adiẹ dami loogun nu, maa fọ ọ lẹyin
Iwọ ati ta a ni?
Emi ma kọ ọ, orilẹede Iran lo sọ pe oun ṣetan lati gbẹsan
Bi Amẹrika ṣe ju ado oloro sibi iko nnkan ija oloro wọn si lana ọjọ Aiku
Olori ologun Iran, Amir Hatami, ni Amẹrika ko ni lọ lai jiya ẹṣẹ rẹ
Fun ẹkunrẹrẹ…
















