Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ẹgbẹ awọn ajijagbara fun ominira Biafra, IPOB, ti kede pe

Simon Ekpa ti awọn agborin fi kele ofin mu ni Finland kii ṣe ọmọ ẹgbẹ awọn, bẹẹ ni kii olori wọn

IPOB lo sọ ọrọ naa ninu atẹjade kan ti agbẹnusọ rẹ, Emmnuel Powerful fi lede lọjọ Eti

Powerful sọ pe awọn ọdaran ati adaluru ni Ekpa n ba dowopọ, ara rẹ lo si n ṣiṣẹ fun

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa loju opo BBC Yoruba

Niluu Abuja

Ọmọ ilẹ okere ti iye wọn le ni ọgọrun ti foju bale ẹjọ lori ẹsun iwa ọdaran ori ayelujara

Lara ẹsun ti ijọba fi kan awọn afuerasi naa ni ike wiwọ atawọn jibiti ori ayelujara mii

Ọsẹ to kọja ni ọwọ ọlọpaa tẹ awọn afurasi naa ti pupọ ninu wọn jẹ ọmọ orilẹede China ati Malaysia

Ti ẹ ba fẹ mọ bo ṣe n lọ