Constitution review: A fẹ́ kí ará ìlú túbọ̀ ráàyè sọ̀rọ̀ nípa ohun tí wọ́n fẹ́ / kò fẹ́ ni- Ajibola Bashir

Oríṣun àwòrán, @Bashir
Kini Ile Igbimọ Asofin Agba fi daa pada fun Akeredolu?
Awọn aṣofin agba naa ti daa pada fun un pe ti ara rẹ lo sọ.
Agbẹnusọ fun ile aṣofin agba, Sẹnetọ Ajibọla Bashiru ni ti ara Akeredolu lo n sọ.
Senetọ Ajibola Bashiru to n ṣoju Osun Central nipinlẹ Osun lo fun un lesi pe ọrọ ko ri bẹẹ.
- Ohun tí wọ́n ní kí òkóbó Buhari bọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àbò ni kó bọ̀, dípò dídúnmọ̀huru mọ́ aráàlú- PDP
- Àbámọ̀ ńlá ń bọ̀ láìpẹ́ fún àwọn tó fẹ́ dojú ìjọba bolẹ̀, a má tó yọ sí wọn- Buhari
- Wo ìdí tó fi ṣeéṣe kí ìjọba àpapọ̀ ó kéde àkọ̀tun ìséde n'ipínlẹ̀ Eko
- Òṣìsẹ̀ 170 tí Ajimobi lé ni Lautech ni ń o gbà padà, owó osù márun wọ́n yoo di sísan- Gómínà Oyo
- Wo ohun ti yóò ṣẹlẹ̀ sí obìnrin tó bá fi ojú rí Orò
- Ilẹ̀ Yorùbá kìí ṣe ibi kátàkárà fún yín, ẹ̀yin àgbà tẹ ń gbárùkù ti ọ̀dọ́ lẹ́yìn láti máa da ìlú rú ẹ sọ́ra - Ẹgbẹ́ YWG
Agbenusọ naa ni ero ọkan gomina Akeredolu lo fi sita yẹn, awọn ara ilu to ku naa ṣi ni anfani lati sọ ero ti wọn naa.
O tun nilẹyin eyi ni awọn Aṣofin yoo wa joko pẹlu ase lati yọ awọn ero ti ko gbadun da ni ti wọn yoo si mu ero to maa mu ilọsiwaju lo.
Awọn aṣofin agba lorilẹ-ede Naijiria ti fun gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu lesi ọrọ rẹ to sọ.
Orọ naa ni pe Akeredolu pe fun wiwọgile ileegbimọ aṣofin apapọ ninu atunṣe iwe ofin orilẹede Naijiria ti awọn aṣofin naa n gbero.
Akeredolu pè fún wíwọ́gilé iléègbìmọ̀ aṣòfin àgbà, àwọn aṣofin àgba ní tẹnu ara rẹ̀ ló ń sọ

Oríṣun àwòrán, twitter/Akeredolu
Akeredolu ninu iwoye rẹ nibi apero finukonu lori atunto iwe ofin naa eyi tawọn aṣoju-ṣofin ṣe nilu Akurẹ ṣalaye pe asiko to fun orilẹ-ede Naijiria lati boju wo bibẹgile eto iṣofin oloju meji ti o n ṣe lọwọ.
Koda, o tun ni ki o si sọọ di ẹyọ kan ninu eyi ti ipinlẹ kọọkan yoo ti ni awọn aṣofin mẹrin lati ṣoju rẹ.
- Ọwọ́ ikọ̀ Amọtẹkun ba Mutiu Abdul-Rasheed, afurasí tó ń ta ẹ̀yà ara èèyàn ní Ibadan
- 'Kò sí ààtò fún òfin Sharia àti ẹtọ àwa ẹlẹsìn Islam nínú Oduduwa Republic, a ò gbà!'
- Wo ohun ti yóò ṣẹlẹ̀ sí obìnrin tó bá fi ojú rí Orò
- Ilẹ̀ Yorùbá kìí ṣe ibi kátàkárà fún yín, ẹ̀yin àgbà tẹ ń gbárùkù ti ọ̀dọ́ lẹ́yìn láti máa da ìlú rú ẹ sọ́ra - Ẹgbẹ́ YWG
- Ọ̀gá àgbà NECO papòdà- Kà nípa bí Ọjọ́gbọ́n Obioma ṣe kú
- Olorì Damilola fi èpè ránṣẹ́ sí 'bàbá' rẹ̀ to ní kò padà sọ́dọ̀ Aláàfin
Akeredolu pè fún wíwọ́gilé iléègbìmọ̀ aṣòfin àgbà, àwọn aṣofin àgba ní tẹnu ara rẹ̀ ló ń sọ
Ati pe eredi ipade itagbangba lori atunto iwe ofin Naijiria ni lati gbọ oniruuru ero ọkan araalu lori rẹ.
Amọṣa o, araalu ni yoo papa pinnu ohun ti wọn ba n fẹ ni ilana agbekalẹ abala kẹsan iwe ofin Naijiria ti ọdun 1999.
Lara awọn ohun ti gomina Akeredolu, ti igbakeji rẹ Lucky Aiyedatiwa ṣoju fun, ṣalaye ni pe iṣẹ aṣofin ko yẹ ko jẹ ajokoti bii ikoko ọbẹ.
Bikoṣe eyi ti awọn aṣofin yoo maa wọle wa ṣe ni atigbadegba.
Bẹẹni ko si yẹ fawọn aṣofin lati gba owo oṣu kankan ti ko han si igbimọ to n pin owo ijọba lorilẹ-ede Naijiria, RMAC
- Nǹkan kò burú tó báyìí ní ọgbọ̀n ọdún sẹ́yìn tí mo kọrin pé kí Ọlọ́run bá wa tún Nàijíríà ṣe- Funmi Aragbaye
- Ìdí tí a fi mú àwọn olùfẹ̀hónúhàn pé wọ́n tẹ òfin ètò ààbò lójú.
- Àwọn ọ̀dọ́ lé kábíyèsí jáde láàfin l'Ondo
- Adigunjalè ja Ọ̀gá ọlọ́pàá àti ẹni mẹ́ta míràn lólè
- Wo ohun ti yóò ṣẹlẹ̀ sí obìnrin tó bá fi ojú rí Orò
- A ti rí ọmọ ilé kéú 11 míì nínú àwón tí agbébọn jí gbé ní ìpínlẹ̀ Niger















