Prince Philip: Ọkọ ọbabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí àtàwọn ẹbí rẹ̀ ti ṣe ẹ̀yẹ ìkẹyìn fún Duke ti Edinburgh

Oríṣun àwòrán, PA Media
Ọbabinrin ilẹ Gẹẹsi atawọn ẹbi rẹ ti ṣe ẹyẹ ikẹyin fun ọkọ rẹ, Duke ti Edinburgh ni Windsor Castle.
Iba eeyan perete, to fi mọ awọn ẹbi atawọn ọmọ oloogbe mẹrin, eyii ti William ati Harry wa lara wọn ni wọn tẹlẹ posi ti wọn gbe oloogbe ọhun si.
Lẹyin naa ni wọn gbe posi ọhun wọ ile ijọsin St. George to wa ni Windsor Castle lori ọkọ ayọkẹlẹ land Rover.
Ni dede aago mẹta ọsan ni wọn ṣe idakẹjẹ oniṣeju kan kaakiri ilẹ Gẹẹsi.
Bo tilẹ jẹ gbagede Windsor Castle ni wọn ti ṣe eto isinkun naa, wọn ko gba ọpọ ero laye nibẹ tabi lawọn ile miran to jẹ ti ori ade ilẹ Gẹẹsi.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Mẹsan an ninu awọn mọlebi ori ade lo tẹlẹ posi Prince Philip, to fi mọ awọn ọmọọba, Anne, Charles, Edward pẹlu Andrew.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Duke ti Cambridge ati ọmọ ọba Harry kọwọrin pẹlu ibatan wọn, Peter Philips.

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Vice Admiral Sir Timothy Laurence ati the Earl ti Snowdon na ko gbẹyin nibẹ.

Oríṣun àwòrán, PA Media
Ki wọn to ṣe idakẹjẹ oni iṣẹju kan ni ọkọ ọbabinri Elizabeth de, to si lo pade Biṣọọbu agba ti Canterbury.

Oríṣun àwòrán, PA Media

Oríṣun àwòrán, Reuters

Oríṣun àwòrán, Reuters

Oríṣun àwòrán, AFP

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, Getty Images


Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, Getty Images
Ọpọ ero lo wo bi eto isinku naa ṣe lọ lati okeere.

Oríṣun àwòrán, Reuters

Oríṣun àwòrán, PA Media
Awọn ọmọ ogun yinbọn soke bi wọn ṣe n gbe oku Prince Philip wọ inu ile ijọsin St. George.

Oríṣun àwòrán, PA Media
Awọn eeyan ilu gbiyanju lati peju sibẹ ṣugbọn wọn ko gba ọpọ ero laaye nitori ilana itakete siraẹni.

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, Mary Evans Picture Library

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Oríṣun àwòrán, Reuters

Oríṣun àwòrán, PA Media

Oríṣun àwòrán, Reuters

Oríṣun àwòrán, Getty Images












