Lagos tanker accident: Ọkọ̀ àjàgbé agbépo kan tún dànù l'Eko

Oríṣun àwòrán, lasema
Ọkọ ajagbe agbepo kan ti ṣubu lagbegbe Shasha nitosi Akowọnjọ nilu Eko.
Ajọ to n mojuto iṣẹlẹ pajawiri nipinlẹ Eko LASEMA ni awsn ti gbe gbogbo igbesẹ to yẹ ni gbigbe lati dẹkun wahala to le fẹ sọ nibẹ.
Alaga ajọ LASEMA, Ọmọwe Olufẹmi Damilsla Oke-Ọsanyintolu ti rọ awọn olugbe agbegbe naa lati ṣe pẹlẹ titi digba ti wọn yoo fi gbe e kuro nibẹ.









