Ìjọba Kaduna: Gbogbo àwọn tó wà nídìí ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn yóò gé ìka jẹ

Nasir El Rufai

Oríṣun àwòrán, @elrufai

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Gomina ipinlẹ Kaduna, Mallam Nasil El-Rufai ti figbe ta pe eeyan mẹrindinlaadọrin ni awọn gende agbebọn sekuta nijọba ibilẹ Kajuru.

El Rufai, ninu atẹjade kan to fisita ni, ọmọde mejilelogun ati obinrin mejila lo fori sọta isẹlẹ ipaniyan naa.

Amọ sa, atẹjade naa ko salayeohun to fa sababi isẹlẹ naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Atẹjade naa wa leri leka pe, gbogbo awọn eeyan to ba lọwọ ninu isẹlẹ isekupani yii ni yoo finmu kata ofin.

Loju opo twitter re, @elrufai, gomina ipinlẹ́ Kaduna foju laifi wo isẹlẹ naa, to si n fewe ọmọ mọ awọn eeyan agbegbe naa leti lati mase gbẹsan.

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post