Àkọlé àwòrán, Ìjọba Nàìjíríà ń san ẹgbẹ̀rún márùn-ún márùn-ún fún awọn ènìyàn to tálákà jùlọ ní orílẹ̀-èdè yìí
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3
Láìpẹ́ yìí ní ìjọba àpapọ̀ kéde láti máà san ẹgbẹ̀rún márùn-ún gba fún àwọn tálaákà lórìlẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Owó yìí ni yóò jẹ́ atọ́nà sáájú pínpín owó Abacha ti wọ́n rí gbà fún àwọn ènìyàn.
Awọn owó ti wọn jí kó tó kù
Àwọn owó tí wọn dá padà
$2-5bn
1998
Ìgbéléwọ̀n àjọ Transparency international fi hàn pé láàárín 2bílìọ̀nù - 5 bílìọ̀nù dọ́là ni owó tí ọ̀gágun Sani Abacha jí kó
$750m
1998
Ọ̀gágun Abdulsalam Abubakar, tó jẹ́ olori orílẹ̀-èdè nígbà náà rí àádọ́talélẹ́ẹ̀dẹ́gbẹ̀rin(750) dọ́là owó gbà lọ́wọ́ àwọn ebí Abacha ní onírúúrú owó ilẹ̀ òkèrè
$64m
2000
Orílẹ̀-èdè Switzerland dá 64 mílìọ̀nù dọ́là pada
$1.2bn
2002
Ààrẹ Obasanjọ bá ìdílé Abacha dìí kí ó ba lè rí 1.2 biliọ̀nù gbà padà
$160m
2003
Wọn gba160 míliọnù dọ́là padà láti Jersey, British Isles. ìjọba Nàìjíríà sọ pe àwọn rí 149 milìọ̀nù dọ́là
$88m
2003
88 milìọ̀nù dọ́la ni ìjọba Switzerland dá padà
$461m
2005
ọ̀kànlélọ́gọ́talénírinwó (461.3) milíọ̀nù dọ́là ni ìjọba Switzerland dá padà. Mínísítà fún ètò ìsúná nígbà náà Ngozi Okonjo Iweala tó tún jẹ ààrẹ Banki àgbáyé sọ pé 458 mílíọ́nù dọ́làní àwọn rí nínú ilé ìfowópamọ́ náà ni wọn ti dá padà.
$44m
2006
mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì dọ́là tí wọ́n dá padà láti orílẹ̀-èdè Switzerland
$227m
2014
ẹtàdínlọ́gọ́riinlénígba (227) mílíọ̀nù dọ́là ni mínísítà ètò ìsúná sọ pé àwọn Liechtenstein
$320m
2017
Oòkòólélọ́dúrún mílíọ̀nù dọ́là ni ìjọba Switzerland dá padà
$308m
2020
Ilẹ̀ Amẹ́ríkà yóò dá $308mowó dọ́là padà fún ìjọba Nàìjíríà látàrí pé wọn yóò lo owó náà fún iṣẹ́ àkànṣe mẹ́ta pàtàkì.

Orísun
Transparency International, ìjọba Nàìjíríà, Banki àgbáyé, Agbejọ́rò àgbà, report Jersey
Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ náà ti wa dí òòtọ́ọ́ báyìí bí ètò náà ṣe ti bẹ̀rẹ̀ ni pẹrẹwu, àwọn ènìyàn kan ní abúlé Ifitedunu, ni ìjọba ìbílẹ̀ Dunukofia nípinlẹ̀ Anambra ló jẹ́ri si ọ̀rọ̀ yìí nígbà ti wọn ń bá BBC Pidgin sọ̀rọ̀.
Àkọlé àwòrán, Kìí ṣe gbogbo ìpínll ni owó náà ti de báyìí
Kìí ṣe gbogbo ìpínlẹ ni owó náà ti de báyìí sùgbọn àwọn àjọ to ń ri sí àmúludùn àti ààbo àrá-ìlú (NASSCO) ti ń lọ káàkiri láti gba orúkọ sílẹ̀ nígbà ti àjọ tó ń ri sí pínpín owó náà yóò máa san owó.
Àkọlé àwòrán, Ìjọba Nàìjíríà ń san ẹgbẹ̀rún márùn-ún márùn-ún fú awọn ènìyàn to tálákà jùlọ ní orílẹ̀-èdè yìí.
Èto ọ̀hún jẹ́ ti Banki àgbáyé láti ran àwọn orilẹ̀-èdè lọ́wọ́ kí ìpín àwọn aláìní ènìyàn baà lè dínkù, sùgbọn wọn ni àwọn ń fi ojú sí owó náà láti rii dájú pé magòmágó ò wáyé.
Àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ lẹ́yìn ọdún 20 tí Abacha kú
Oríṣun àwòrán, Getty Images
Àkọlé àwòrán, Ọ̀pọ̀ ènìyàn kò gba ọ̀rọ tí Dokita íjọba sọ pé àìsàn ọkàn ló pa á
Ogun ọdun ti kọja lẹyin ti Ọgagun Sani Abacha to jẹ adari orilẹ-ede Naijiria lọdun 1993 si 1998 ku iku ojiji.
Sani Abacha to jẹ ọmọ bibi ilu Kanuri lati ipinlẹ Borno. O lọ si ile iwe ọlogun ti Kaduna ko to gba oye ọgagun lọdun 1963.
Titi di oni to jẹ ayajọ ọjọ ti oloogbe naa papoda, ọ̀pọ̀ awọn ọmọ Naijiria ko sọ nkan rere nipa rẹ lori ẹrọ ayelujara
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts
End of X post, 2
Awọn miran fẹsun kan an pe, o lu ọpọlọpọ owo ilu ni ponpo nigba aye rẹ, ati pe awọn eniyan gbagbọ pe obinrin lo se iku pa a.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
Warning: Third party content may contain adverts
End of X post, 4
Amọ, Aarẹ Naijiria, Muhammadu Buhari ati awọn ọmọ Naijiria miran gbagbọ pe asiko rẹ tu eniyan lara nitori ipese ohun amayedẹrun bii ina ijọba, ọna to gbooro, ẹkọ ọfẹ ati eto ilera fun awọn eniyan.