BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Orilẹede Zimbabwe
Ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ lórí ìwọ́de láti yọ ààrẹ ilẹ̀ Zimbabwe torí pé ìlú le
1 Ìgbé 2025
Ọmọ ọdún mẹ́jọ jáde láàyè lẹ́yìn tó lo ọjọ́ márùn-ún pẹ̀lú kìnìún bí ogójì nínú igbó
3 Sẹ́rẹ́ 2025
0:56
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,56
3 Sẹ́rẹ́ 2025
Ìjọba buwọ́lu òfin tó wọ́gilé ìdájọ́ ikú
8 Èrèlè 2024
Èèyàn 123 pàdánú ẹ̀mí wọn nípasẹ̀ ààrùn kọ́lẹ́rà ní Zimbabwe ní oṣù mẹ́jọ
1 Bélú 2023
Mnangagwa borí ìbò ààrẹ Zimbababwe fún sáà kejì
27 Ògún 2023
Ètò ìdìbò sípò ààrẹ̀ ńlọ lọ́wọ́ lórílẹ̀èdè Zimbabwe
23 Ògún 2023
Àna ààrẹ Mugabe ń béèrè fún dúkìá tó tó $80m àti àwọn nǹkan míì lẹ́yìn tí ọmọ ààrẹ kọ̀ọ́ sílẹ̀
5 Èbibi 2023
Ọmọ ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí ní Zimbabwe, Robert Mugabe kó sí gbaga ọlọ́pàá
21 Èrèlè 2023
Pásítòͅ kú lásìkò ààwèͅ ogójì oͅjóͅ tó gbà bíi ti Jesu
18 Èrèlè 2023
Adájọ́ kú sórí òrùlé Ṣọ́ọ̀ṣì lẹ́yìn tí wọ́n ní ó pa ìyàwó rẹ̀, tún bá òkú rẹ̀ sún lójú àwọn ọmọ wọn
11 Ọ̀pẹ̀̀ 2022
Ṣé òótọ ni pé àwọn ọ̀dọ́ ń torí $40k gé ọmọ ìka ẹsẹ̀ wọn tà? BBC gbé èsì ìwádìí jáde
2 Òkùdu 2022
Èèyàn 60 l'erin ti pa láàrín ọdún yìí nìkan lórílẹ̀èdè Zimbabwe
12 Èbibi 2022
Erin tẹ obìnrin kan àti ọmọ rẹ̀ pa lọ́jọ́ ọdún
5 Sẹ́rẹ́ 2022
Wọ́n ti iléèwòsàn pa nítorí àwọn àlùjànú tó n fi ipá bá àwọn nọ́ọ́sì lòpọ̀
21 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Kò sí ọmọ Zambia kan tó má sùn pẹ̀lú ebi mọ́ lásìkò tèmi gẹ́gẹ́ bíi Aàrẹ- Hichilema ṣèlérí
26 Ògún 2021
Kàyéèfì! Ọwọ́ tẹ òkú tó ń ká àwọn èèyàn mọ́lé, to sì ń jà wọ́n lólè dúkìá
28 Èbibi 2021
Iṣẹ́ aṣẹ́wó ti gbọ̀pọ̀! Wọn kò gba owó mọ́, wo ohun tí wọn ń gbà báyìí
26 Èbibi 2021
Babaláwo rí ẹ̀wọ̀n he! lẹ́yìn tó ṣe ìwòsàn fún obìnrin pẹ̀lu tábà fínfín, ló bá kú lójijì!
24 Ìgbé 2021
Ohun tó ṣẹlẹ̀ rèé níbi ìsìnkú Ginimbi ọ̀dọ́mọdé olówó tó kú lẹ́ni ọdún 36
14 Bélú 2020
Ṣe lóòtọ́ ni ejò ń pọ owó fún Ginimbi, ọ̀dọ́mọdé olówó kó tó jáde láyé?
14 Bélú 2020
Ìkúnlẹ̀ abiyamọ, ìkókó mẹ́jọ kú nílé ìwòsàn lálẹ́ ọjọ́ kàn
29 Agẹmo 2020
Ṣé kìí ṣe pé orílẹ̀-èdè Zimbabwe tún fẹ́ dàwó lẹ́ẹ̀kan sí?
17 Òkùdu 2020
Ìyàwó igbákejì ààrẹ Zimbabwe dèrò àgọ ọlọ́pàá lórí ẹ̀sùn jẹgúdújẹrá
16 Ọ̀pẹ̀̀ 2019
Page
1
nínú
2
1
2
Tókàn
You might also like:
news
|
sport
|
weather
|
worklife
|
travel
|
future
|
culture
|
world
|
business
|
technology