Zimbabwe: Ìjọba fẹ̀sùn kan obìrin mẹ́ta lẹ́gbẹ́ alátakò, wọ́n d'éléẹjọ́ bọ̀

Orílẹ̀-èdè Zimbabwe léti bèbè dídàwó lẹ́ẹ̀kan si
Àkọlé àwòrán, Joana Momombe, okan ninu awon obinrin mẹta ti wọ́n fẹ̀sùn kan
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 6

Inu omije lawọn obinrin mẹtẹta wa pẹlu aṣọ idọti aṣọ ẹlẹwọn ti wọn wọ ninu gbaga apoti ijẹjọ nile ẹjọ majisireeti ni olu ilu orilẹede Zimbabwe, Harare ti wọn n duro de idajọ boya wọn yoo jẹ ki wọn gba beeli wọn.

Ni lọọlọ yii, Zimbabwe jẹ ilu to ṣe pe kii ṣe Coronavirus nikan lo n ba wọn finra, to fi mọ iṣoro ọrọ aje to jinra atọrọ oṣelu pẹlu. Koda laarin eyi ọrọ igbimọpọ fẹ gbajọba eyi to n fa gbọnmi si omi o to laarin ijọba to wa lori oye ati ẹgbẹ oṣelu alatako, gbogbo eyi lo kun iṣoro orilẹede Zimbabwe.

"Orilẹede wa jẹ eyi o n gbogun ti ara ilu rẹ", agbẹnusọ fun ẹgbẹ alatako Movement for Democratic Change (MDC), to wa nibi igbẹjọ naa lọjọ aje to si bi wọn ṣe doju ti awọn obinrin yii wa lara ọgbọn oṣelu ati ko ibẹru sọkan awọn araalu.

Ajafẹtọmọniyan lawọn obinrin mẹta ọhun lẹgbẹ oṣelu MDC ti wọn si n foju wina ofin lori ẹsun pe wọn parọ pe wọn ji awọn gbe wọn si fipa ba wọn lopọ loṣu to kọja.

Emmerson Mnangagwa gbajọba lọ́dun 2017

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Àkọlé àwòrán, Orílẹ̀-èdè Zimbabwe léti bèbè dídàwó lẹ́ẹ̀kan si

Nigba ti wọn n sọrọ nileewosan lẹyin ohun ti wọn ni awọn la kọja, awọn obinrin ọhun ni awọn ẹṣọ orilẹede kan lo fiya jẹ awọn.

Ṣugbọn lọgan ni awọn minisita ijọba kan fẹsun kan wọn pe wọn yi irọ ninu itan ni lati tabuku ba ijọba ati lati yi oju ijọba kuro lara ikopa awọn obinrin yii ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin.

Akọwe ijọba lori iroyin, Nick Mangwana sọ pe "awọn obinrin mẹtẹta yii wa lara awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu MDC to tapa si ofin isede lorilẹede lati lọ kopa ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin".

Igbakeji minisita kan to pada gba idaduro lo dabaa pe aṣẹwo ni awọn obinrin naa eyi ti ọkan lara wọn jẹ aṣofin.

"Aimoye igba ni wọn ti tan wa jẹ".

Ṣugbọn iṣẹlẹ yii kan mu ki ohun gbogbo lọju pọ loju awọn ara Harare ni. "Ko sohun tuntun mọ labẹ ọrun", dokita ileewosan kan to saba maa n tọju awọn to fara gba iṣẹlẹ ifipabanilopọ lo sọ eyi.

Iṣẹlẹ ọhun waye lasiko to nira fun Zimbabwe. O tun wa yi biri ni nkan bi ọdun mẹta sẹyin nigba ti awọn ologun fi tipa tipa gba ijọba lọwọ aarẹ Robert Mugabe ati ẹni to gbe ọpa aṣẹ le lọwọ, Emmerson Mnangagwa eyi to mu atunto ba ọrọ aje wọn ati ijọba to ni ọwọ mimọ lasiko ẹgbẹ oṣelu Zanu-PF wa ni ijọba.

Ẹwẹ, lonii idaji iye awọn to wa ni orilẹede naa lo nira fun lati ri ounjẹ jẹ, ọwọn gogo to tun wa ba ọrọ aje wọn jẹ ni o le lọdun mẹwaa sẹyin.

ọlọpàá àti ẹgbk alatako ni Zimbabwe

Oríṣun àwòrán, EPA

Àkọlé àwòrán, Orílẹ̀-èdè Zimbabwe léti bèbè dídàwó lẹ́ẹ̀kan si

Minisita fun ọrọ abẹnu, Kazembe Kazembe sọ lọsẹ to kọja pe "ko sohun to jọ mọ ifipagbajọba. O da ẹbi yii sori ọrọ gbọyi sọyii laarin awọn ologun abẹle ati awọn orilẹede agbaye". Inu omije lawọn obinrin mẹtẹta wa pẹlu aṣọ idọti aṣọ ẹlẹwọn ti wọn wọ ninu gbaga apoti ijẹjọ nile ẹjọ majisireeti ni olu ilu orilẹede Zimbabwe, Harare ti wọn n duro de idajọ boya wọn yoo jẹ ki wọn gba beeli wọn.

Ni lọọlọ yii, Zimbabwe jẹ ilu to ṣe pe kii ṣe Coronavirus nikan lo n ba wọn finra, to fi mọ iṣoro ọrọ aje to jinra atọrọ oṣelu pẹlu. Koda laarin eyi ọrọ igbimọpọ fẹ gbajọba eyi to n fa gbọnmi si omi o to laarin ijọba to wa lori oye ati ẹgbẹ oṣelu alatako, gbogbo eyi lo kun iṣoro orilẹede Zimbabwe.

"Orilẹede wa jẹ eyi o n gbogun ti ara ilu rẹ", agbẹnusọ fun ẹgbẹ alatako Movement for Democratic Change (MDC), to wa nibi igbẹjọ naa lọjọ aje to si bi wọn ṣe doju ti awọn obinrin yii wa lara ọgbọn oṣelu ati ko ibẹru sọkan awọn araalu.

Ajafẹtọmọniyan lawọn obinrin mẹta ọhun lẹgbẹ oṣelu MDC ti wọn si n foju wina ofin lori ẹsun pe wọn parọ pe wọn ji awọn gbe wọn si fipa ba wọn lopọ loṣu to kọja.

Nigba ti wọn n sọrọ nileewosan lẹyin ohun ti wọn ni awọn la kọja, awọn obinrin ọhun ni awọn ẹṣọ orilẹede kan lo fiya jẹ awọn.

Ṣugbọn lọgan ni awọn minisita ijọba kan fẹsun kan wọn pe wọn yi irọ ninu itan ni lati tabuku ba ijọba ati lati yi oju ijọba kuro lara ikopa awọn obinrin yii ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin.

Akọwe ijọba lori iroyin, Nick Mangwana sọ pe "awọn obinrin mẹtẹta yii wa lara awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu MDC to tapa si ofin isede lorilẹede lati lọ kopa ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin".

Igbakeji minisita kan to pada gba idaduro lo dabaa pe aṣẹwo ni awọn obinrin naa eyi ti ọkan lara wọn jẹ aṣofin."Aimoye igba ni wọn ti tan wa jẹ".

Ṣugbọn iṣẹlẹ yii kan mu ki ohun gbogbo lọju pọ loju awọn ara Harare ni. "Ko sohun tuntun mọ labẹ ọrun", dokita ileewosan kan to saba maa n tọju awọn to fara gba iṣẹlẹ ifipabanilopọ lo sọ eyi.

Iṣẹlẹ ọhun waye lasiko to nira fun Zimbabwe. O tun wa yi biri ni nkan bi ọdun mẹta sẹyin nigba ti awọn ologun fi tipa tipa gba ijọba lọwọ aarẹ Robert Mugabe ati ẹni to gbe ọpa aṣẹ le lọwọ, Emmerson Mnangagwa eyi to mu atunto ba ọrọ aje wọn ati ijọba to ni ọwọ mimọ lasiko ẹgbẹ oṣelu Zanu-PF wa ni ijọba.

Ẹwẹ lonii idaji iye awọn to wa ni orilẹede naa lo nira fun lati ri ounjẹ jẹ, ọwọn gogo to tun wa ba ọrọ aje wọn jẹ ni o le lọdun mẹwaa sẹyin.

Minisita fun ọrọ abẹnu, Kazembe Kazembe sọ lọsẹ to kọja pe "ko sohun to jọ mọ ifipagbajọba. O da ẹbi yii sori ọrọ gbọyi sọyii laarin awọn ologun abẹle ati awọn orilẹede agbaye".Inu omije lawọn obinrin mẹtẹta wa pẹlu aṣọ idọti aṣọ ẹlẹwọn ti wọn wọ ninu gbaga apoti ijẹjọ nile ẹjọ majisireeti ni olu ilu orilẹede Zimbabwe, Harare ti wọn n duro de idajọ boya wọn yoo jẹ ki wọn gba beeli wọn.

Ni lọọlọ yii, Zimbabwe jẹ ilu to ṣe pe kii ṣe Coronavirus nikan lo n ba wọn finra, to fi mọ iṣoro ọrọ aje to jinra atọrọ oṣelu pẹlu. Koda laarin eyi ọrọ igbimọpọ fẹ gbajọba eyi to n fa gbọnmi si omi o to laarin ijọba to wa lori oye ati ẹgbẹ oṣelu alatako, gbogbo eyi lo kun iṣoro orilẹede Zimbabwe.

"Orilẹede wa jẹ eyi o n gbogun ti ara ilu rẹ", agbẹnusọ fun ẹgbẹ alatako Movement for Democratic Change (MDC), to wa nibi igbẹjọ naa lọjọ aje to si bi wọn ṣe doju ti awọn obinrin yii wa lara ọgbọn oṣelu ati ko ibẹru sọkan awọn araalu.

Ajafẹtọmọniyan lawọn obinrin mẹta ọhun lẹgbẹ oṣelu MDC ti wọn si n foju wina ofin lori ẹsun pe wọn parọ pe wọn ji awọn gbe wọn si fipa ba wọn lopọ loṣu to kọja.

Nigba ti wọn n sọrọ nileewosan lẹyin ohun ti wọn ni awọn la kọja, awọn obinrin ọhun ni awọn ẹṣọ orilẹede kan lo fiya jẹ awọn.

Ṣugbọn lọgan ni awọn minisita ijọba kan fẹsun kan wọn pe wọn yi irọ ninu itan ni lati tabuku ba ijọba ati lati yi oju ijọba kuro lara ikopa awọn obinrin yii ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin.

Akọwe ijọba lori iroyin, Nick Mangwana sọ pe "awọn obinrin mẹtẹta yii wa lara awọn ọdọ ẹgbẹ oṣelu MDC to tapa si ofin isede lorilẹede lati lọ kopa ninu ifẹhonuhan to lodi si ofin".

Igbakeji minisita kan to pada gba idaduro lo dabaa pe aṣẹwo ni awọn obinrin naa eyi ti ọkan lara wọn jẹ aṣofin."Aimoye igba ni wọn ti tan wa jẹ".

Ṣugbọn iṣẹlẹ yii kan mu ki ohun gbogbo lọju pọ loju awọn ara Harare ni. "Ko sohun tuntun mọ labẹ ọrun", dokita ileewosan kan to saba maa n tọju awọn to fara gba iṣẹlẹ ifipabanilopọ lo sọ eyi.

Iṣẹlẹ ọhun waye lasiko to nira fun Zimbabwe. O tun wa yi biri ni nkan bi ọdun mẹta sẹyin nigba ti awọn ologun fi tipa tipa gba ijọba lọwọ aarẹ Robert Mugabe ati ẹni to gbe ọpa aṣẹ le lọwọ, Emmerson Mnangagwa eyi to mu atunto ba ọrọ aje wọn ati ijọba to ni ọwọ mimọ lasiko ẹgbẹ oṣelu Zanu-PF wa ni ijọba.

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: Third party content may contain adverts

End of X post

Ẹwẹ, lonii idaji iye awọn to wa ni orilẹede naa lo nira fun lati ri ounjẹ jẹ, ọwọn gogo to tun wa ba ọrọ aje wọn jẹ ni o le lọdun mẹwaa sẹyin.Minisita fun ọrọ abẹnu, Kazembe Kazembe sọ lọsẹ to kọja pe "ko sohun to jọ mọ ifipagbajọba. O da ẹbi yii sori ọrọ gbọyi sọyii laarin awọn ologun abẹle ati awọn orilẹede agbaye". Ọrọ tirẹ dabi eyi to wa latọdọ alatako.

"Iji n ja wa, iji pataki ni. Orilẹede wa ti n kuna", eyi ni ikilọ oniṣowo kan, Shingi Muyeza, nigba ti wọn ṣe ipade onifọnran ori ayelujara Zoom pẹlu awọn oṣiṣẹ ijọba lori iṣoro ọrọ aje to n doju kọ wọn lọwọlọwọ ati eyi ti Coronavirus naa n da silẹ.

Ṣe iṣẹlẹ ifipagbajọba mii le waye?

Ibẹrubojo to wa ni Harare lọwọlọwọ tun ti le kenka sii pẹlu ọwọ ti awọn oṣiṣẹ alaabo tilẹ n gbe lati ja olu ileeṣẹ ẹgbẹ alatako gba to fi mọ bi awọn ikọ amuṣẹya ṣe n tu si igboro lati mu ibọwọ fofin isede ni dandan fawọn araalu.