Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é ma gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Bísọ́ọ̀bù kan ti ri ikú he níbi tó ti n parí ìjà fun tọkọtaya

Ah! iyẹn ma tun lagbara kẹ, boo lọrọ ṣe jẹ?

Ọkọ iyawo gun olori ijọ Rapture Empowerment International niluu Osogbo, Biṣọọbu Olaribigbe Greatness lasiko to n ni gbolohun asọ ọhun

Mo gbọ pe Biṣọọbu Olaribigbe ko ṣẹṣẹ maa ba wọn pari ija?

Oo parọ! Ileeṣẹ ọlọpaa ni tọkọtaya naa ti wa ni ahamọ awọn bayii

Ọti amuju kii bimọ ọ re... (read it as if you are singing)

Ee ti jẹ, mo ro pe o kii muti ni?

Bẹẹ ni o. Ọlọpaa kan lo ti wọ gau ni Zambia lẹyin to ṣi afurasi mẹtala silẹ lahamọ pe ki wọn o lọ ṣajọyọ ọdun tuntun

Awọn alaṣẹ sọ pe Titus Phiri ti mu ọti yo lasiko to huwa naa

Ọmọdekunrin kan ti jade laaye lẹyin to lo ọjọ marun un ninu igbo tawọn kiniun wa

Lai ki n ṣe Danieli inu bibeli

Eyi fẹ ju bẹẹ lọ nitori iroyin ni awọn kiniun to wa ninu igbo Matusadona Game Park ni Zimbabwe to ogoji

Ha! Bawo lo ṣe debẹ?

Fun ẹkunrẹrẹ awọn iroyin yii

Kò ṣe á má gbọ̀ ọ́