Russia 2018: Àwòrán nọ́mbà jẹẹsí Super Eagles fún Russia rèé

Àkọlé fídíò, Super Eagles: Àwòrán nọ́mbà jẹẹsí Super eagles fún Russia rèé

Ajọ NFF ti fi orukọ ati nọmba jẹẹsi awọn agbabọọlu Super eagles ti yoo kopa ninu idije ife ẹyẹ agbaye ni Russia sita.

Itupalẹ rẹ niyi ni atẹ isalẹ yii:

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: