Wo bí àwọn Egúngún ṣe dá àrà sílẹ̀ ní orílẹ̀èdè Benin

Àkọlé fídíò, Ọdun Egungun ni orilẹede Benin
Wo bí àwọn Egúngún ṣe dá àrà sílẹ̀ ní orílẹ̀èdè Benin

Awọn agba bọ wọn ni ibi gbogbo la n dana alẹ ọbẹ kan dun ju ara wọn lọ ni.

Ọdun Egungun jẹ eyi to gbajumọ nilẹ adulawọ, paapaajulọ laarin iran Yoruba.

Ni orilẹede Benin, BBC News Yoruba bawọn ṣe ajọyọ ọdun Egungun nibi ti ilu orin ijo ati are Egungun ti gbilẹ gidigidi.

Nibi ajọdun naa, ọpọlọpọ Egungun kaakiri agbaye ni wọn peju ba wọn ṣe ajọyọ naa.

Oniruuru egungun – Onijo, alare ati ọlọrẹ ni wọn wa nikalẹ fun ọdun naa.

Ẹ gbadun gbogbo bo ṣe lọ ninu fọran fidio yii.