Russia 2018: Gernot Rohr kéde orúkọ agbábọ́ọ̀lù 23

Oríṣun àwòrán, @thenff
Akọnimọọgba ikọ Super Eagles, Gernot Rohr, ti kede oruko awọn agbabọọlu metalelogun ti wọn yoo ṣoju orilẹede Naijiria ninu ife ẹyẹ agbaye ti yoo waye ni Russia.
Balogun ikọ Super Eagles Mikel Obi, Ogenyi Onazi, Wilfred Ndidi ati Oghenekaro Etebo wa lara awọn agbabọọlu aarin gbungbun ti wọn wa lori iwe naa.
Oju opo Twiitter ajo to'n risi ere boolu lorileede Naijiria ni wọn fi ikede naa si.
This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.
End of X post
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
Awọn asọle to wa lori iwe orukọ naa ni Ikechukwu Ezenwa, Daniel Akpeyi ati Francis Uzoho.
Awọn ololufẹ ere bọọlu l'orilẹede Nàìjírìa ti n foju sọna fun iwe orukọ tipẹ ko to jade lonii.








