Wo àwọn aṣojú 65 tí Ààrẹ Tinubu fi ránṣẹ́ sílẹ̀ òkèèrè àti ìlú tí wọ́n ti ń ṣojú wa

Aworan awọn aṣoju si ilẹ okeere tuntun

Oríṣun àwòrán, INEC/RENO/IKPEAZU/FANI-KAYODE/FACEBOOK

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Aarẹ Bola Tinubu ti buwọlu awọn aṣoju orilẹede si ilẹ okeere marundinladọrin ti wọn yoo lọ ṣoju orilẹede Naijiria ni awọn orilẹede mii ati ajọ iṣokan agbaye.

Igbesẹ yii ni igbagbọ wa pe yoo mu ajọsepọ Naijiria dan mọ ran pẹlu awọn orilẹeede yooku.

Agbẹnusọ aarẹ, Bayo Onanuga lo kede eyi ninu atẹjade kan to fi lede fun awọn akọroyin.

Ninu oṣu kejila ni ileeṣẹ aarẹ fi orukọ awọn aṣoju yii ransẹ si ile igbimọ aṣofin fun ayẹwo ati ibuwọlu.

Skip X post
Allow X content?

This article contains content provided by X. We ask for your permission before anything is loaded, as they may be using cookies and other technologies. You may want to read X cookie policy and privacy policy before accepting. To view this content choose 'accept and continue'.

Warning: The BBC is not responsible for the content of external sites.

End of X post

Eyi ni orukọ awọn aṣoju si ilẹ okeere

1. Grace Bent – Lome, Togo

2. Ita Enang – South Africa

3. Ikpeazu Victor – Spain

4. Nkechi Linda Ufochukwu - Tel-Aviv, Israel

Skip podcast promotion and continue reading
Èyí ni ìkànnì Whatsapp wa

Àjáàbalẹ̀ ìròyìn BBC News Yorùbá lórí WhatsApp rẹ

Darapọ̀ mọ́ wa nibì

End of podcast promotion

5. Mahmud Yakubu: Qatar

6. Paul Oga Adikwu - Di Vatican City Holy See

7. Vice Admiral Ibok-Ete Ekwe Ibas - The Philippines

8. Reno Omokri - Mexico City, Mexico

9. Abasi Ebraimah - Budapest, Hungary

10. Erelu Angela Adebayo - Portugal

11. Olumilua Oluwayimika Ayotunwa - Tokyo, Japan

12. Ugwuanyi Ifeanyi Lawrence - Athens, Greece

13. Chioma Priscilla Ohakim - Poland

14. Aminu Dalhatu - United Kingdom

15. Abdulrahman Bello Dambazau - Beijing, China

16. Tasiu Musa Maigari - Gambia

17. Olufemi Pedro - Australia

18. Muhammed Ubandoma Aliyu - Argentina

19. Lateef Kayode Are - United States of America

20. Joseph Sola Iji - Russia

21. Jimoh Ibrahim - Ajọ UN

22. Femi Fani Kayode - Germany

23. Prof. Isaak Folorunsho Adewole - Ottawa, Canada

24. Ajimobi Fatima Florence - Austria

25. Lola Akande - Sweden

26. Ayodele Oke - France

27. Yakubu Gambo - Saudi Arabia

28. Prof. Nora Ladi Daduut - Seoul, South Korea

29. Onueze Chukwujika Okocha - Dublin

30. Kulu Haruna Abubakar - Tunis, Tunisia

31. Jerry Samuel Manwe - Port of Spain, T&T

Awọn aṣoju si okeere ti ẹka ti Career

1. Nwabiola Ezenwa Chukuwemeka - Cote D'Ivoire

2. Besto Maimuna Ibrahim - Niger

3. Monica Okwuchukwu Enebechi - Sao Tome, STP

4. Mohammed Mahmud Lele - Algiers, Algeria

5. Endoni Synoph Paebi - Ouagadougou, Burkina Faso

6. Ahmed Mohammed Monguno - Cairo, Egypt

7. Jane Adams - Kingston, Jamaica

8. Clark-Omeru Alexandra - Lusaka, Zambia

9. Chima Geoggrey David - Bamako, Mali

10. Odumah Yvonne Ehinosen - Malabo, E/Guinea

11. Wasa Segun Ige - Beirut, Lebanon

12. Ruben Abimbola Samuel - Rome. Italy

13. Onaga Ogechukwu Kingsley - Maputo, Mozambique

14. Magaji Umar - Kinsasha, DR Congo

15. Muhammed Saidu Dahiru - New Delhi, India

16. Abdulssalam Habu Zayyad - Dakar, Senegal

17. Shehu Ilu Barde - Accra, Ghana

18. Aminu Nasir - Ethiopia

19. Abubakar Musa Musa - N'Djamena, Chad

20. Haidara Mohammed Idris - The Hague, Netherlands

21. Bako Adamu Umar - Rabat, Morocco

22. Sulu-Gambari Olatunji Ahmed - Malaysia

23. Romata Mohammed Omobolanle - Tanzania

24. Shaga John Shamah - Botswana

25. Salau Hamza Mohammed - Tehran, Iran

26. Ibrahim Danlami - Kenya

27. Ibrahim Adeola Mopelola - Cotonu, Benin

28. Ayeni Adebayo Emmanue - Brussels, Belgium

29. Akande Eahab Adekola - Berne, Switzerland

30. Arewa Esther - Windhoek, Namibia

31. Gergadi Joseph John - Libreville, Gabon

32. Luther Ogbomode Ayo-Kalata - Sierra-Leone

33. Danladi Yakubu Nyaku - Khartoum, Sudan

34. Bello Dogon-Daji Haliru - Bangkok, Thailand