Kí ni Ooni Ile Ife lọ ṣe lọ́dọ̀ Ààrẹ àná lórílẹ̀èdè Nàìjíríà?

Oríṣun àwòrán, bashirahmad/x
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Ọọni ile Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi, Ọjaja keji bẹ aarẹ ana lorilẹede Naijiria, Muhammadu Buhari wo ni ile rẹ to wa ni Daura ni ipinlẹ Katsina.
Ko si atẹjade kankan to jade lẹyin abẹwo naa lati sọ eredi abẹwo naa amọṣa àwọn ọba kan ba Olori alade ilẹ Yoruba naa kọwọrin.

Oríṣun àwòrán, bashir Ahmad/x

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmad/x
Ọkan lara awọn amugbalẹgbẹ fun aarẹ tẹlẹ naa, Ahmad Bashir ṣalaye ninu awọn fọto abẹwo naa to fi sita loju opo X rẹ.
O ni ki ọbalaye naa to fi ilu Katsina silẹ, oun ati Muhammadu Buhari tun ṣe abẹwo si aafin Emir ilu Daura.

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmad/ x

Oríṣun àwòrán, Bashir Ahmad/ x








