Buhari: Ààrẹ di ẹ̀bi àìrí iṣẹ́ ṣe ru àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà torí àwọn ìgbésẹ̀ kan tí wọn gbé

Oríṣun àwòrán, The africa report.com
Aarẹ orileede Naijiria, Muhammadu Buhari ti ṣalaye idi ti ọpọ ọdọ Naijiria ko fi ri iṣẹ ṣe, eyi to ni ko sẹyin akoba to waye lasiko iwọde ENDSARS.
Ninu ifọrọwero ti aarẹ ti kopa lori eto akanṣe ileeṣẹ amounmaworan Arise TV ni o ti fi ọrọ yii lede.
Buhari ni awọn ọdọ to kawe gboye rẹpẹtẹ le ma ri iṣẹ nitori iwa ti awọn eeyan kan hu.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo ọ̀nà tí ọ̀pọ̀ èèyàn fi fẹ́ sàmí June 12 lọ́la, tí ariwo fi gbalẹ̀
- Wo ọ̀rọ̀ tí ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá ní Nàìjíríà sọ lórí ìfẹ̀hónúhàn June 12
- Ìrora iṣẹ́ abẹ ìdí tí mo ṣe pọ̀jù, mò ń kú lọ, mo fẹ́ padà sí bí mo ṣe wà tẹ́lẹ̀ - Bobrisky
- Wo àwọn orílẹ̀èdè mẹ́rin l‘Afrika tó ṣetán láti ra iná ìjọba láti Naijiria
- Bí mó bá fojú kan Baba Wande lórí ìtàgé, ṣe ní ẹ̀rù máa ń bà mí - Tafa Oloyede
- Àwọn tí a jọ ń se ìjọba ní Nàìjíríà sisẹ́ gba ipò wọn lábẹ́ ìjọba mi ni- Aarẹ Buhari
- Ẹ̀yin òṣèré tíátà, kò sí iṣẹ́ ọ̀fẹ́ mọ́, ẹ sanwó iṣẹ́ tẹ bá gbé fún mi - Funmi Awelewa
- Ẹyìn ọ̀dọ́ Nàìjíríà ẹ tún ìwà yín ṣẹ tí ẹ bá fẹ́ kí ìṣòro àìríṣẹ́ dòpin
O ni ipalara ati biba nkan jẹ to wyae lasiko iwde ENDSARS to lati le awọn to ba fẹ doko owo ni Naijiria kuro.
''Lọ ba eyikeyi Gomina ki o s fun pe ki o fun ẹ ni iṣẹ tabi agbaṣe iṣẹ yoo sọ fun ọ pe ko si aaye.Bẹẹ lọrọ ri lọdọ awọn ijọba ibilẹ naa.''
O ni tori eyi pupọ ọdọ le kawe gboye ṣugbọn wọn le ma ri iṣẹ titi ti wọn yoo fi jade laye.
''Idi ni pe ko si ẹni ti yoo fi owo rẹ doko owo layika ti ko ba si ifọkanbalẹ. Nitori naa ni mo fi sọ fun awọn ọdọ pe ti wọn ba fẹ iṣẹ, ki wọn ṣe pẹlẹ pẹlẹ''
Aarẹ tun tọka si awọn ọkọ akero igba, ti wọn dana sun ni ipinlẹ Eko, eyi ti Gomina Ambode ra .
''Ta ni yoo wa da ileeṣẹ silẹ nigba ti ko ba si ifọkanbalẹ? Ko si.''
Nkan ti mo n sọ yii ko gba ọgbọn pupọ. Ẹ ṣe jẹjẹ, ti alaafia ba wa nilu awọn eeyan yoo wa lati dokowo ti yoo mu iṣẹ wa''

Oríṣun àwòrán, The africa report.com

Mo kọ̀ láti sọ̀rọ̀ nípa fí f'òfin de 'Twitter' báyìí sùgbọ́n a ti sí isẹ́ àkànse Deep Blue ti NIMASA- Buhari

Oríṣun àwòrán, Muhammadu Buhari/Facebook
Ẹwẹ, Aare Muhammadu Buhari ti ṣe abẹwo si ilu Eko ni guusu Iwo Oorun Naijiria.
Nibe lo ti kopa ninu eto ifọrọwanilẹnuwo aladase pẹlu ileese Amohunmaworan Arise TV.
Nibi ifọrọwanilẹnuwo yii ni Aare Buhari ti ni oun kọ lati sọrọ nipa ofin ti ijọba oun fi de "Twitter"
- Iléesẹ́ Twitter ti ń bá ìjọba Nàìjíríà sọ̀rọ̀ papọ̀- Alhaji Lai Mohammed
- Àjọ EFCC mú àwọn afurasí aàdọ́ta tó ń lu jìbìtì lórí ayélujára ní Ibadan
- Ẹ̀yin olóṣèlú, ẹ má fi ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn Igangan dá ìjà ẹlẹ́yàmẹ̀yà sílẹ̀- YWG
- Orílẹ̀-ède 174 káàkiri àgbáyé ní ìwọ́de Yoruba Nation yóò tí wáyé ní June 12- Ẹgbẹ́ Yoruba One Voice
- Ìbínú ńlá ti mú Àǹjọ̀nú tó ń jẹ́ Emmanuel lọ....àwọn kan ń sọ̀fọ̀ Lucifa tó lọ- Okotie
Buhari ni oun ko ni dahun ibeere igba ti Twitter yoo bẹrẹ isẹ pada ni Naijiria lasiko naa.
O ni awo mọ sinu, mọ sikun ni oun fi da.
Bakan naa ni Aarẹ Buhari sisọ loju eegun isẹ akanse ti Nigerian Maritime Administration and Safety Agency (NIMASA).
Eyi ti wọ́n pe ni Deep Blue Project.
Awọn miran ti wọn jọ si eto naa ni: Femi Gbajabiamila to jẹ abẹnugan ile igbimọ Asofin ni Abuja, Gomina Sanwo Olu ti ipinle Eko, Gomina ipinlẹ Ekiti, Oyo, Ogun ati igbakeji gomina Ondo.
Bakan naa ni Seneto Gbemisola Saraki, Minista eto irinna ati minista abẹlẹ to n mojuto eto irinna ni Naijiria.
- Orí mi wú pé àkòkò ìjọba mi ní àṣeyọrí reluwé ń wáyé - Buhari
- Ìbínú ńlá ti mú Àǹjọ̀nú tó ń jẹ́ Emmanuel lọ....àwọn kan ń sọ̀fọ̀ Lucifa tó lọ- Okotie
- Orílẹ̀-ède 174 káàkiri àgbáyé ní ìwọ́de Yoruba Nation yóò tí wáyé ní June 12- Ẹgbẹ́ Yoruba One Voice
- Ẹ̀yin olóṣèlú, ẹ má fi ìṣẹ̀lẹ̀ ìpànìyàn Igangan dá ìjà ẹlẹ́yàmẹ̀yà sílẹ̀- YWG
Ọlọ́pàá àti ológun kò ní lójú àánú mọ́ fáwọn abàlújẹ́, ìyàtọ̀ yóò wà - Buhari
Buhari: A má a lo òfin tó ní kí wọn mú màálù tó bá jẹ oko títí tí olówó rẹ̀ yóò fi sanwó
Aarẹ Orilẹede Naijiria, Muhammadu Buhari ti ni ominu n kọ oun nipa ẹkun iwọ oorun ariwa Naijiria , nibi ti awọn eeyan to jẹ ẹya kan naa ti n pa ara wọn.
Aarẹ Buhari woye ọrọ yii lasiko to n kopa lori eto ifọrọwerọ kan pẹlu ileesẹ mohunmaworan kan, to si ni ijọba yoo kan si wọn nibamu pẹlu ede ti wọn gbọ.
"Awọn eeyan yii ti wọn dijọ n sọ ede kanna ni wọn n pa ara wọn, ti wọn si tun n ji maalu ara wọn, ti wọn tun n jo abule ara wọn.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Wo ilúbìnrin tí wọn ti ń ní ìbálòpọ̀, bímọ̀ láì ní ọkọ
- Ìpínlẹ̀ Eko ń gbàlejò Ààrẹ Muhammadu Buhari lónìí
- Ẹ̀yin tẹ̀ ń pè fún ìyapa Nàíjíríà, òmùgọ̀ pátápátá ni yín - Obasanjo
- Kàyééfì! Ìyàwó bímọ mẹ́wàá lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, ọkọ kò níṣẹ́ lọ́wọ́
- Sunday Igboho ní òun ṣetán láti dira fáwọn ọ̀dọ́ Ibarapa fún ìpèsè ààbò aráàlú
- Àṣìta ìbọn pa ọkùnrin kan ní Ilesa níbi táwọn afurasí ẹlẹgbẹ́ òkùnkùn ti fìjà pẹ̀ta
- Iléesẹ́ Twitter ti ń bá ìjọba Nàìjíríà sọ̀rọ̀ papọ̀- Alhaji Lai Mohammed
- Àjọ EFCC mú àwọn afurasí aàdọ́ta tó ń lu jìbìtì lórí ayélujára ní Ibadan
- Ọ̀gbìn igbó kìí ṣe irúgbìn èṣù, ẹ pa èrò àtijọ́ tì, oríṣun ọrọ̀ ajé ni - Akeredolu
A ti fun awọn ọlọpa atawn ologun ni agbara lati mase loju aanu lawọn ọsẹ diẹ sasiko yii, iyatọ yoo si wa.
Tẹ ba jẹ kawọn eeyan lọ sisẹ ninu oko wọn, ebi yoo pa ilu, tijọba yoo si wọ wahala nla, eyi ti a ko fẹ ko sẹlẹ nitori a ti koju isoro to ga to."
Buhari ni oun ti se ayipada awọn ọga ologun, ta si ba wọn se ipade pọ pẹlu ni aimọye igba.
"A gba wọn laaye lati lọ kaakiri lọ wo ipo ti nnkan wa funra wọn, ta si sọ pe a fẹ ki alaafia wa, ki awsn eeyan le pada sinu oko wọn lati dako.
Amọ a ko pariwo sita pupọ, ki awọn ẹni ibi ma baa mọ, amọ awọn eeyan to wa lẹnu isẹ agbofinro mọ ohun ribiribi ta n se."
Mo ti sọ fawọn gomina lati lọ pese aabo si ipinlẹ koowa wọn
Nigba to n sọrọ lori idasilẹ ileesẹ ọlọpaa lawọn ipinlẹ kọọkan, aarẹ Buhari ni oun ti sọ fun awọn gomina pe ki wọn lọ finmu finlẹ labẹle.
"Wọn ko le joko kalẹ lẹyin ti wọn ba wọle ibo gomina tan, ki wsn si lero pe emi ni maa ma sisẹ fun wọn, mo ti ran wọn pada."
Nigba to n sọrọ lori bi ẹya kan se n gba ipo giga ju awọn ẹya miran lọ, aarẹ Buhari ni ko yẹ ki wọn maa fi awọn eeyan sipo nitori pe wọn wa lati ẹya kan.
O ni bi eeyan kan ba se dangajia si ni oun maa n wo, bi wọn ba se sisẹ kaakiri si, pẹlu iye ọdun ti wọn fi ni iriri lẹnu isẹ bii ọdun mẹẹdogun si mejidinlogun.
Darandaran ti ẹran rẹ ba jẹ oko oloko, ko sanwo rẹ ni
Lori ọrọ bi awọn darandaran se maa n da ẹran kiri loju taye, aarẹ Buhari ni oun ti ni ki wọn wa akọsilẹ ofin ijọba kan jade eyi to n safihan awọn oju ọna maalu ati agbegbe ifiẹran jẹko.
Ofin naa ni pe darandaran ti ẹran rẹ ba jẹ oko oloko, ki wọn mu ẹran naa pamọ, titi ti olowo rẹ yoo fi sanwo oko to jẹ.
O ni awọn darandaran n ko ara wọn nijanu lasiko naa nitori iwọnba ni awọn darandaran to wa, ta si mọ awọn oju ọna ti wọn le gba, o rọrun lati mọ awọn ọna naa.
"Asa ka maa sare wa silu Abuja lo n fa wahala yii. Gomina ipinlẹ Benue si ni mo jẹ ọkan lara wọn amọ n ko jiyan rẹ.
Ohun ti mo n sọ ni pe darandaran ni Naijiria ko legbe ju ọpa lọ amọ awọn eleyi ti n gbe ibọn AK 47.
Awọn Fulani to n wa lati orilẹede Mauritania atawọn agbegbe miran si jọ awọn ọmọ orilẹede yii, eyi to mu ki awọn eeyan maa mu omulomu
Ma pada sinu oko mi, ti mo ba fi ipo aarẹ silẹ
Nigba to n sọrọ lori ohun to kan to fẹ se to ba kuro nipo aarẹ tan, Muhammadu Buhari ni oun ko pa oko oun ti , oun si setan lati pada sibẹ.
"Mo si n sọ fun awọn ọmọ Naijiria pe mo nifẹ lati se daadaa si wọn.
Lootọ la si nilo ilọsiwaju lẹkun iwọ oorun guusu Naijiria, ila oorun guusu, amọ lọwọlọwọ bayii, ẹkun iwọ oorun ariwa Naijiria lo n kọ mi lominu pupọ nitori ibẹ lo n gbona janin-janin lọwọ."




















