Nigeria Twitter ban: Iléesẹ́ Twitter ti ń bá ìjọba Nàìjíríà sọ̀rọ̀ papọ̀- Alhaji Lai Mohammed

Lai Mohammed

Oríṣun àwòrán, @Lai Moammed

Iléesẹ Twitter ti setán láti bá ìjọba Nàijíríà sọrọ papọ- Lai Mohammed

Alhaji Ali Mohammed to je minsita fun ifitonileti ati asa ni Naijiria ni pe ileesẹ Twitter ti ijọba Naijiria fofin de lọjọ Eti ti setan lati ba ijọba sọ asọepọ.

Lai Mohammed sọrọ yii fawọn akọroyin nile ijọba lẹyin ti wọn pari ipade igbimọ amusẹse ijọba apapọ.

O ni ileeseẹ lọjọru oni ni ileesẹ Twitter ti kan si ijọba Naijiria lati jọ sọrọ papọ lori ifofin de tijọba se.

Àkọlé fídíò, Tunde Gbadamosi: Kìí ṣe Tinubu ní ipò ààrẹ̀ tọ́ sí, ìgbà wo ní ìtan ajá ń kan lèmọ́mù?

Lai Mohammed ni ijọba fofin de Twitter nitori idunkooko mọ ni awọn bii IPOB, Kanu Nnamdi ati ipa ti Twitter ko ninu iwọde #EndSARS.

Lai Mohammed tun ni lati isinyii yatọ si Twitter, awọn ileese ọrọ ayelujara bii Facebook, Instagram ma nilo lati forukọ silẹ ni Naijria bayii.

Àkọlé fídíò, Ayelala Idol: Onímọlẹ̀ ní olúwẹri obìnrin ni òrìṣà náà ló ṣe ń pọn omi sínú ẹlẹ́ṣẹ̀

Lai Mohammed ni ominira lati sọrọ yii wa ni Naijiria nipa se lilo nkan mii yato si Twitter.