Baba Ijesha: Princess ní òun yóò borí, ó le má wáyé lójú ẹsẹ̀ àmọ́ ó di dandan

Adẹrinposonu nni, Adekola Adekanla, ti ọpọ eeyan mọ si Princess ti paroko ọrọ ransẹ lori bi Baba Ijesha se ri beeli gba.
Princess, tii se iya ọmọdebinrin ti wọn ni Baba Ijesha ba se asemase, ti wa gbe aworan kan soju opo Instagram rẹ lati paroko ọrọ ransẹ.
Ohun to wa ninu aworan naa ni ọkunrin kan to n fo lọ loju ofurufuru.
- Iyabo Ojo fèsì lórí béèlì tí wọ́n fún Baba Ijesha
- Baba Ijesha gba béélì níléẹjọ́ Májísírétì, àmọ́ ọ̀rọ̀ kù kó tó jáde l’àhámọ́
- Ẹ fi Baba Ijesha sílẹ̀ fún mi, màá ṣe onídùróó rẹ̀ - Yomi Fabiyi
- Màá pe Kọ̀mísánà ọlọ́pàá Eko àti igbákejì rẹ̀ lẹ́jọ́ lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha - Amofin
- ''Àwa àgbààgbà òṣèré kò dákẹ́ lórí wàhálà láàrin Iyabọ Ojo ati Yomi Fabiyi nitori Baba Ijẹsha''
- 'Nígbá tí a rí Baba Ijesha lónìí ní Panti, ohun tójú wa rí, ẹnu kò lè sọ o!'
- Ṣé lóòtọ́ ni Iyabo Ojo ti bẹ Yomi Fabiyi lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha tó wà ní Panti?
Lara aworan naa ni wọn si kọ ọrọ kan si wipe "Maa bori, o le maa jẹ loju ẹsẹ amọ o di dandan"
Bakan naa lo kọ ọrọ si ẹgbẹ akọle naa pe Ọlọrun kii sun, Ọlọrun fẹran ọmọde, ẹ mase ba ọmọde se asemase.

Oríṣun àwòrán, Princesscomedian/Instagram
O tun tẹsiwaju pe ẹ kẹyin si iwa ifipabanilopọ, ẹ sọrọ sita tẹ ba ri ohunkohun.
Ọrọ yii lo kọ ni deede aago mẹwa alẹ ọjọ Isẹgun lẹyin ti iroyin gbalẹ kan pe adajọ ti fontẹ lu pe ki wọn fun Baba Ijesha ni beeli.
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Ẹ̀yin ọdọ́, ẹ sọ́ra fún ìtànjẹ láti darapọ̀ mọ́ ìyapa Naijiria - YAF
- Sunday Igboho, jọ̀ọ́ má gbé ìwọ́de Yoruba Nation wọ Iseyin - Aseyin ṣèkìlọ̀
- Sunday Igboho lọ sọ́dọ̀ Guru Maharaji lórí ìdásílẹ̀ Yoruba Nation
- "Sunday Igboho kò fí lààkáyé kún ìjìjàgbara rẹ̀ nípa àtakò sí ìbò 2023"
- Mò ń wá olè tó jí nńkan ní ọọ́físì mi, ẹ̀bùn owó iyebíye rèé - Afeez Eniola
- Ohun tó ṣẹlẹ̀ ní ìlú Modakeke àti Ile Ife
- Ṣé lóòtọ́ọ́ ni Baba Ijesha ti jáde ní àhámọ́ ọlọ́pàá?
Ọpọ awọn ololufẹ adẹrinposonu naa si lo ti n fesi lori ohun ti Princess kọ yii, lati fi lọkan rẹ balẹ pe Ọlọrun wa lori itẹ.


















