Ọ̀ṣun Oṣogbo 2019: Ìyán gbígbóná ní wọn kọ́ fi bẹ̀rẹ̀ ọdún
Àkọlé àwòrán, Iwaju aafin ti n rọ kẹkẹ fun ọdunÌye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1
Àkọlé àwòrán, Ẹ poore yeeeye ooo, Ọṣun jọọ, fun wa lowo, fun wa ni ọmọ, fun wa ni alaafiaÀkọlé àwòrán, Iya olomi tutu ti Osogbo naa ti setan ọdunÀkọlé àwòrán, Iyan gbigbona ni aarọ ni awọn obinrin kọkọ monutoÀkọlé àwòrán, Haa, ọrọ yii gba ki awọn ọkunrin gba odo iyanÀkọlé àwòrán, Tọmọde-tagba lo ti n ta mọra lati mura fun ọdunÀkọlé àwòrán, Bi awọn ọkunrin se n palẹmọ, naa ni awọn ọkunrin n seÀkọlé àwòrán, Aje yoo kuku bu igba jẹ́ fun awọn eeyan kan loniiÀkọlé àwòrán, Ọrọ̀ aje yii naa ko yọ awọn ọkunrin silẹ, tọkunrin-tobinrin lo n wa owoÀkọlé àwòrán, Bi esinsin ba ta firi, awa setan lati wọn lasiko ọdun ni awọn agbofinro yii n wiÀkọlé àwòrán, Ni ṣẹpẹ la wa fun ọdun Ọṣun ni ọdun yii, ọdun yii ko yẹ