YCE: Kunle Olajide ní káwọn ọ̀dọ́ dìde torí ọjọ́ ọ̀la wọn kò ṣe e fọ́wọ́ ẹ sọ̀yà
Naijiria ko ni eto iṣejọba to la iṣẹ onikaluku ninu oṣelu silẹ- Kunle Olajide
Oloye Kunle Ollajide to jẹ akọwe gboogboo fun Igbimọ agba Yoruba lo fidi ọrọ yii mulẹ.
O ni ilẹ Yoruba lo ni ogun abẹle julọ ninu itan Naijiria, ni eyi ti o fi beere pe ṣe iran Yoruba ti ṣetan lati se ara wọn ni ọkan bayii?
Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Mò ṣì ń ṣépè lọ́wọ́lọ́wọ́ fáwọn ọ̀rẹ́ tó ní kí ń ṣiṣẹ́ abẹ ìdí - Bobrisky
- Jide Kosoko, tí mo bá tú àṣírí rẹ, àwọn ọmọbìnrin rẹ yóò dọwọ́ bojú - Nkechi Blessing yarí
- Mo dẹ́kun àdúrà gbígbà lẹ́yìn ikú Ajimobi - Florence aya olóògbé
- Oríire dé! Aláànú kan fún Kemisola ní ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ dé fásitì
- Omo Borty sọ̀rọ̀ sókè lórí ìbáṣepọ̀ rẹ̀ àti Dino Melaye
- Òǹyẹ̀ kò lè yẹ ìwọ́de Yoruba Nation l‘Eko, mò ń bọ̀ níbẹ̀ - Sunday Igboho
- Obasanjo fèsì lórí báwọn ọmọ Nàìjíríà kan ṣe ń pe ààrẹ Buhari ní Jubril ti Sudan
Kunle Olajide ni ẹni to ba ti dagba ju ẹni ọdun marundinlaadọrin 65 lọ ko yẹ lati dije dupo kankan mọ bayii.
Titi di isinyi, O ni |Naijiria ko i tii bọ lọwọ ologun ninu ero ti oun.
- Wo àwọn ìlànà tí ó máa tẹ̀lé láti wo èsì ìdánwò 2021 Jamb UTME rẹ lórí ayélujára àti SMS
- Ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo àti àwọn ẹlẹ́sìn àbáláyé bẹ̀rẹ̀ àjọṣepọ̀ láti fí opin sí ìṣoro ètò aàbò
- Gọngọ́ sọ, àwọn Ṣọ́jà lé ọlọ́pàá lùgbẹ́ lágọ́ ọlọ́pàá l' Osogbo
- Wo iléẹ̀kọ́ tí wọ́n kò ti fààyè gba akẹ́kọ̀ọ́ láti padà sọ́dọ̀ Òbí tàbí ìlú rẹ̀ lẹ́yìn tó bá parí
- Ọmọ ọdún méje ni mo ti ń digunjalè, ogun ìdílé ló fàá, afurasí ṣàlàyé l'Ondo
Olajide ni ọrọ Naijiria da bi ti ẹni to n gbe ẹsẹ meji siwaju to n gbe mẹrin sẹyin ni .
Bakan naa lo ni ki awọn to n beere fun Oodua Nation tẹsiwaju ninu ijijangbara naa.
- Iyabo Ojo, mẹ́nu kúrò lórí ọ̀rọ̀ Baba Ijesha ní báyìí tí ọ̀rọ̀ ti dé iwájú mi - Adájọ́ Toyin Taiwo
- Àwọn adigunjalè kọ lẹ́tà sí adúgbò, wọ́n ni kí ara àdúgbò dá 20m tàbí kí wọ́n ó jàwọ́n lólè
- Wo àwọn ìlànà tí ó máa tẹ̀lé láti wo èsì ìdánwò 2021 Jamb UTME rẹ lórí ayélujára àti SMS
- Èèyàn kan ti kú, 99 di àwátì lẹ́yìn tí ilé alájà méjìlá wó lulẹ̀ l'óru
- Sínímá Abebi tí mo kọ́kọ́ ṣe jẹ́ ẹ̀bùn ọjọ́ ìbí tí Ìyá mi fún mi- Fisayo Amodemaja