Àwọn àwòrán mánigbàgbé láti ibi ìsìnkú Rotimi Akeredolu

Awọn obinrin ilu Owo tu jade láti dagbere fun gomina Akeredolu
Iyawo, àwọn ọmọ ati ọmọ-ọmọ oloogbe Rotimi Akeredolu duro leti iboji láti dagbere

Oríṣun àwòrán, Olawale Abolade

Àkọlé àwòrán, Iyawo, àwọn ọmọ ati ọmọ-ọmọ oloogbe Rotimi Akeredolu duro leti iboji láti dagbere
Iyawo oloogbe, Arabinrin Betty Akeredolu rèé to n bu erupẹ sì oku ọkọ rẹ ninu iboji

Oríṣun àwòrán, Olawale Abolade

Àkọlé àwòrán, Iyawo oloogbe, Arabinrin Betty Akeredolu rèé to n bu erupẹ sì oku ọkọ rẹ ninu iboji
Igbakeji aarẹ Naijiria,Kashim Shettima naa wa sibi eto isinku Akeredolu niluu Owo
Àkọlé àwòrán, Igbakeji aarẹ Naijiria,Kashim Shettima naa wa sibi eto isinku Akeredolu niluu Owo
Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu, wa lara àwọn gomina to ṣe ẹyẹ ikẹyin fun akẹẹgbẹ́ wọn to lọ
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Eko,Eko, Babajide Sanwo-Olu, wa lara àwọn gomina to ṣe ẹyẹ ikẹyin fun akẹẹgbẹ́ wọn to lọ
Gomina ipinlẹ Kano nigba kan, Abdullahi Ganduge, naa kopa nibi eto isinku Akeredolu
Àkọlé àwòrán, Gomina ipinlẹ Kano nigba kan, Abdullahi Ganduge, naa kopa nibi eto isinku Akeredolu
Àwọn olukẹdun

Oríṣun àwòrán, BBC

Wọn fi aṣọ iṣẹ awọn ẹsọ alaabo Amotekun ṣe ẹyẹ ikẹyin fun Akeredolu. Ipa kekere kọ ni oloogbe naa ko ninu idasilẹ ileeṣẹ alaabo naa nilẹ Yoruba
Àkọlé àwòrán, Wọn fi aṣọ iṣẹ awọn ẹsọ alaabo Amotekun ṣe ẹyẹ ikẹyin fun Akeredolu. Ipa kekere kọ ni oloogbe naa ko ninu idasilẹ ileeṣẹ alaabo naa nilẹ Yoruba
Inu ọgba yii ni wọ́n sin Rotimi Akeredolu si niluu Owo, to jẹ ilu abinibi rẹ
Àkọlé àwòrán, Inu ọgba yii ni wọ́n sin Rotimi Akeredolu si niluu Owo, to jẹ ilu abinibi rẹ
Wọn tẹ oloogbe ni itẹ ẹyẹ

Oríṣun àwòrán, Bbc

Bamu ni ile ijọsin St. Andrews Cathedral niluu Owo kun, fun ero to wa ṣe isin idagbere fun oloogbe
Gbogbo oju ọna ni awọn eeyan pe si lati wo Akeredolu fun igba ikẹyin
Àkọlé àwòrán, Gbogbo oju ọna ni awọn eeyan pe si lati wo Akeredolu fun igba ikẹyin
Tọmọde-tagba lo tu yaaya jade si oju ọna lati wo Akeredolu fun igba ikẹyin

Oríṣun àwòrán, Bbc

Àkọlé àwòrán, Tọmọde-tagba lo tu yaaya jade si oju ọna lati wo Akeredolu fun igba ikẹyin
Iyawo ati ọmọkùnrin Akeredolu niyii ninu ile ijọsin St. Andrews Cathedral, Owo
Àkọlé àwòrán, Iyawo ati ọmọkùnrin Akeredolu niyii ninu ile ijọsin St. Andrews Cathedral, Owo
Pẹlu ẹdun ọkàn ati ikaanu ni àwọn araalu Owo fi dagbere fun ọmọ wọn, Rotimi Akeredolu to d'oloogbe
Àkọlé àwòrán, Pẹlu ẹdun ọkàn ati ikaanu ni àwọn araalu Owo fi dagbere fun ọmọ wọn, Rotimi Akeredolu to d'oloogbe