Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ileeṣẹ ọmọ ogun Naijiria ti kede pe ẹgbẹ agbesumọmi tuntun mii ti bẹrẹ si n ṣọṣẹ ni Naijiria

Agbẹnusọ ileeṣẹ naa, Edward Buba sọ pe, ipinlẹ Sokoto ati Kebbi ni wọn ti n ṣọṣẹ lọwọ yii

O fi kun pe ẹgbẹ ọhun, ti orukọ rẹ n jẹ ‘Lukarawas’ ni ajọṣepoọ pẹlu awọn agbesunmọmi agbegbe Mali Ati Niger

Kan soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ

Nipinlẹ Ondo

Oludije sipo gomina ninu ẹgbẹ oṣelu ZLP, Abass Mimiko ti tako ẹgbẹ oṣelu PDP

Lẹyin ti sọ pe, ajọ INEC gbọdọ paarọ olori oṣiṣẹ rẹ nipinlẹ naa, Oluwatoyin Babalola, ṣaaju eto idibo gomina

PDP sọ pe ipinlẹ Ondo ni obinrin naa dagba si, o si ṣeeṣe ki APC lo o lati ṣe makaruru lọjọ idibo

Hmmmmmm

Amọ awọn onimọ ti da si ọrọ naa ati ibi to ṣeeṣe ko ja si

Fun alaye ni kikun