Àwọn nnkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa àwọn olùdíje nínú ìdìbò ààrẹ Ghana

Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Ọjọ Abamẹta, ọjọ kẹjọ, oṣu Kejila, ọdun 2024, ni eto idibo aarẹ yoo waye ni orilẹ-ede Ghana.

Lara awọn to n dije lati gba ipo lọwọ Aarẹ Nana Akufo-Addo, ni igbakeji rẹ, Mahamudu Bawumia, ẹni ọdun mọkanlelọgta.

Bakan naa ni aarẹ orilẹ-ede naa nigba kan, John Dramani Mahama, naa tun n dije lati pada di aarẹ.

Awọn oludije gboogi mẹrin